EJIOGBE-WPS Office
EJIOGBE-WPS Office
EJIOGBE-WPS Office
1. Ayooyo go, ayooyo go, ayooyo gomo gomo adifa fun orunmila baba nlo re bawon muyo yora, nje awa
ta bawon muyo yora, oro ibanuje kan ko ni de bawa, oro ibanuje kan kii de bayo.
2. Iyonyo iyonyo adifa fun orunmila nijo ti omo araye ni awon ko ni yo fun baba mo, orunmila ni oro ni
wonpa, o ni eke ni won se, o ni eni toba lowo lowo niwon n yo fun, iyonyo iyonyo, ifa je ki won o yo fun
mi, iyonyo iyonyo, eni toba nire gbogbo la n yo fun, iyonyo iyonyo, ifa jeki won o yo fun mi, iyonyo
iyonyo.
3. Ori ekuru ni o ran, emu ekuru ni o koro, agbede gbede meji ekuru ni o funni lorun dunrin dunrin adifa
fun folawiyo eyi tin somo ora nife, eyi tiwon ni ko febo ola le, ebo omo ni koma se, folawiyo nikan lo se
ebo ola losi sebo omo.
4. Kaaka ribiti ka fibon ti, eruku toro a mon yo, eruku a si mo taala bole adifa fun ayilegbe orun eleyi ti
yio fi alapa segun ota re tuurutu, koma wo lota pa, ogiri alapa, koma wo lota pa, ogiri alapa, sango n
bawo re segun.
5. Orunmila lo didi, ifa mo lo didi, idi ni gbepon gbepon nfi gbepon, idi ni onjeyo fin jeyo adifa fun
layimoju eyi tin se iya ejiogbe, oun sebo ebo re kofin, o n setutu, etutu re ko da, wonni ko kara giri, ebo
ni wonni kose, o gbebo o rubo, o gberu o teru, nse ebo layimoju omo yin re o, ara orun e gba.
6. Taaba tiji ki a mon ki olowo ori eni, olowo ori eni la n pefa adifa fun ejiogbe oun nawo sire titi owo re
ko tore, wonni ko kara giri, ebo ni wonni kose kole ba nire gbogbo laye, o gbebo o rubo, o gberu o teru,
nse oyeku meji mo ki o loni o, too to, daadan baba nse fori bale fomo, iwori meji, odi meji, gbogbo oju
odu mo kiyin loni o, too to dandan, baba nse fori bale fomo, eropo ero ofa, eyin komo pe eni ba fori bale
ni oun ni ire gbogbo.