Yoruba Year One Week 5: Eya Ara (Parts of The Body)

Download as pptx, pdf, or txt
Download as pptx, pdf, or txt
You are on page 1of 6

YORUBA YEAR ONE

WEEK 5
EYA ARA
(PARTS OF THE BODY)
ATUNBOTAN EKO
Leyin idanilekoo yii, awon akekoo yoo le ;

1. Daruko awon eya ara ti a le fi oju ri


2. So oruko awon eya ara wonyii ni ede Yoruba.
EYA ARA ( PARTS OF THE BODY)
EYA ARA NI EDE YORUBA
Olorun da gbogbo eniyan ni aworan ara re. A ni
ara kan pelu eya pupo ti o si ni orisirisi ise ti
won n se.
Eyi ti a le foju ri ni wonyii;-
EYA ARA

Ori (head)
Oju (eye)
Eti (ear)
Imu (nose)
Ejika (shoulder)
Orun (neck)
  ya (chest)
A
Apa (arm)
Ikun (stomach) Igunpa (elbow)
Idodo (navel)
Owo (hand)
Ika (fingers)

Itan (thigh)
Orunkun (knee)

Ika ese (toes) Ese (leg)


ORIN
ORIN (SONG)
Ori mi , Ejika My head , My shoulder
Orukun, Ese My knee, My toes
Tireni Oluwa they all belong to Jesus.
ISE SISE
Daruko awon wonyii ni ede Yoruba.

1. Head ___________________

2. Neck ____________________

3. Knee ____________________

You might also like