Basic 9 First Term Yoruba L2

Download as docx, pdf, or txt
Download as docx, pdf, or txt
You are on page 1of 26

YORUBA LANGAUGE SCHEME OF WORK

BASIC 9 SAA KIN-IN-NI

OSE AKOONU ISE

1. Às̩ à igbeyawo: Awon ohun to se koko ninu asa igbeyawo. Igbese to je


mó̩ igbeyawo.

2. Oyun nini,itoju oyun,ibimo ati ikomojade.

3. Odun ibile Yoruba.

4. Gbolohun ede yoruba.

5. Ayoka Oni-soro gbesi(Dialogue).

6. Ayoka(Comprehension)

7. ISINMI RANPE(MID-TERM BREAK)

8. Ikini ti o nise pelu isele ati ise(Yoruba greetings that has to do with
events and occupations) .

9 EBI(FAMILY)

10. IBEERE ATI IDAHUN.(Questions and Answer)

11. ATUNYEWO IDANILEKOO SAA YII/ IDANWO.


Ò̩ SÈ̩ KIN- IN-NI (WEEK1)

AKORI:ASA IGBEYAWO:ILANA IGBEYAWO AYE ATIJO) (YORUBA


TRADITIONAL MARRIAGE)

Asa igbeyawo je okan pataki ninu awon asa ti Yoruba gbe laruge.Igbeyawo ni
siso okunrin ati obinrin ti won ti balaga papo bi oko ati iyawo.

Orís̩ ìí o̩nà méjì ni ìgbéyàwó pín sí, àwo̩n ni:

a. Ìgbéyàwó òde-òní.(Modern marriage)


b. Ìgbéyàwó abínibí (Traditional marriage)

PATAKI IGBEYAWO(PURPOSE OF MARRIAGE)

1.Ki a le maa bi si.(It is for reproduction of children)

2.Ki a le je oluranlowo fun ara wa.(It is for companionship)

3.O je ona pataki lati dekun agbere lawujo. (It helps to prevent adultery)

4.O maa n je ki a ri omo ran nise.(In other to send children on erand)

5.Ki a le ri omo jogun eni.(In other to see children to inherit us)


ÀWO̩N ÌGBÉSÈ̩ ÌGBÉYÀWÓ ABÍNIBÍ.(Steps for yoruba
traditional marriage)
i. Ìfojúsóde (Searching)
ii. Ìwádìí (Investigation)
iii. Alárinà (Middle man)
iv. Ìto̩ro̩ (Seeking hands in marriage)
v. Ìs̩ íhùn/Ìjóhe̩ n/Bàbá/Ìyá gbó̩ . (parental consent)
vi. Ìdána (Engagement)
vii. Pàtàkì ìbálé (Value of virginity).

AKOONU ISE

1. Às̩ à igbeyawo: Awon ohun to se koko ninu asa igbeyawo. Ìgbésè̩ to je


mó̩ igbeyawo.

Orís̩ ìí o̩nà méjì ni ìgbéyàwó pín sí, àwo̩n ni:(we have two types of marriage)

c. Ìgbéyàwó òde-òní.(modern marriage)


d. Ìgbéyàwó abínibí.(traditional marriage)

ORÍS̩ÌÍ ÌGBÉYÀWÓ ÒDE-ÒNÍ (TYPES OF MODERN MARRIAGE)

1. Ìgbéyàwó kóòtù (court marriage)


2. Ìgbéyàwó s̩ ó̩ ò̩ s̩ ì (church marriage)
3. Ìgbéyàwó mo̩s̩ álás̩ í/yìgì (Islamic marriage)

ÀWO̩N OHUN ÈLÒ ÌGBÉYÀWÓ ABÍNIBÍ.

OROGBO(bitter kola) ATAARE(aligator pepper) OBI(kolanut)


IREKE(sugar cane) IYO(salt) EMU(palm wine)

OTI(wine) AWON ESO(fruits)

AWON OHUN ELO IDANA(Engagement items)

1. Ogójì Is̩ u (40 tubers of yam)


2. Oyin (honey)
3. Iyò̩ (salt)
4. E̩ja ààrò̩ (cat fish)
5. Epo pupa(palm oil)
6. Obì (kolanut)
7. Orógbó (bitter kola)
8. O̩tí (alcoholic or non-alcoholic drink)
9. Ìrèké (sugarcane)
10. Owó-orí (dowry)
11.Ogójì Is̩ u (40 tubers of yam)
12.Oyin (honey)
13.Iyò̩ (salt)
14.E̩ja ààrò̩ (cat fish)
15.Epo pupa(palm oil)
16.Obì (kolanut)
17.Orógbó (bitter kola)
18.O̩tí (alcoholic or non-alcoholic drink)
19.Ìrèké (sugarcane)
20. Owó-orí (dowry)

IGBELEWON

Daruko awon ohun elo idana fun igbeyawo abinibi ni ile yoruba.

ISE ASETILEWA

1. Ò̩ nà meloo ni igbeyawo pin si? (How many forms of marriage in the
above note?)
2. Ò̩ nà meloo ni igbeyawo òde-òní pín sí? How many forms of modern
marriage do we have?
A. Méjì (2)
B. Mé̩ ta (3)
D. Mé̩ rin (4)
E. Méje.

IWE ITOKASI:Oyebamiji Mustapha(2009:35-45)EKO EDE


YORUBA TITUN JSS 2.Ibadan,University Press P.L.C.
Ò̩ SÈ̩ 2. (WEEK 2)

AKORI:Oyun nini,itoju oyun,ibimo ati ikomojade.

Ìtó̩ jú Aláboyún(Pregnancy and its care,childbirth and naming ceremony)

Oy5n n7n7 wz f5n t[k[taya.*t-j5 oy5n xe pztzk8 p5p= n7tor7 p3 =kan n7n5 zw[n
8d7 pztzk8 ti [k6nrin fi ni aya, ti ob8nrin fi n n7 [k[ ni lati n7 -m= n7l2. *d7 n8y7
ti o fi j1 p3 b7 ob8nrin bq ti l9y5n n7 k3t3 ti o de il3 [k[, inu zw[n cbi [k[ ati cbi
tir2 pzqpzq y99 d6n, w[n y99 s8 mq a x4t-j5 oy5n y87, w[n yoo s8 mq a vzd5rz k7
{l-run s= - kal2 lqy= ati zlzqf7z.
Yor6bq ka zgzn s7 arung5n, bi cni b12 bq s8 k5 si ip0 y87, a kzq si cni t7 9 k5
zk5run.
*T_J% OY%N N& +NZ AB&NIB&(traditional ways of pre-natal care)
1. D7de Oy5n
2. Zw2b7: <Easy labour bathing soap>.
3. On7x4g6n av2b7 l9 mq a t-j5 aboy5n t7 y99 fi b7m[, y90 mq a lo 00g6n b7 i
00g6n 00y8 oj5, 00g6n ooru in5 abbl.< Traditional mid-wives will be treating
the woman till she delivers)
4. {xc – ab7w1r1. <She will be using traditional soap to make her deliver safely)

5. Alqboy5n k0 v[d= xe ixc avqra. <A pregnant woman must not over labour
herself >.
6. {k[ alqboy5n t9 jc [dc v-d= x-ra p7pa zw[n abzm8 cranko n7 zk9k0 t7 8yzw9 r2
bq wz n7n5 oy5n. <The husband of any pregnant woman that is an hunter must not
kill mysterious animals like deer, alegator.
*T_J% OY%N N& )DE-)N&(modern ways of pre-natal care)
1. Il3 8w0szn ni zw[n aboy5n mq a n l[.
2. )0g6n 0y8nb9 ni w-n n l0 x6v-n w-n mq a n x[ 00g6n l0 f5n aboy5n.
3. W-n mq a n xe 8dqnil1k=- f5n zw[n alqboy5n, zw[n n-=s8 av2b7 ni o mq a n
xe 4y7.
4. W-n mq a n va zw[n alqboy5n n7m=rzn lqti mq a jc cja, cyin, 2f-, cran,
ew3b2, zw[n o5njc t9 f5n ara l9kun zti avqra zti zw[n 4so l9r7x87r7x87.

+NZ LQTI D$NZ ZB&K% (Ways and how to prevent still-birth)


1. N7n7 0ye j1n9tq7p6 2j2 t[k[taya. AA/AA tzb7 AA/AS, l4 f1ra lq8 s7 8b2r6
b7b7 [m[ alq8szn.
2. X7xe zy2w0 oy5n n7 il3 8w0szn l90r4k90r4.
3.V7va ab1r1 zjcsqra alqboy5n, k9 p3 p3r3p3r3.
4. J7jc o5njc afqral9kun n7n5 oy5n.

IGBELEWON

Menuba awon ona marun-un ti a n gba toju oyun ni aye atijo.

ISE ASETILEWA

Ko ona marun-un ti a le gba toju oyun ni ode oni.

IWE ITOKASI: IWE ITOKASI:Oyebamiji Mustapha(2009:75-


82)EKO EDE YORUBA TITUN JSS 2.Ibadan,University Press
P.L.C.
Ò̩ SÈ̩ KETA(WEEK 3).

Odun ibile Yoruba. (Yoruba Traditional Religion)

Odun ibile :Eyi ni asiko kan pato ti a ya soto fun bibo awon orisa, nitori pe
gbogbo won lo ni olusin.Bee si ni okookan wonloni ojubo ati abore ti won.
Okanlenirinwo(401) ni gbogbo awon orisa ile Yoruba. Lara won ni;

AWON ORISA ILE YORUBA(YORUBA TRADITIONAL IDOLS)

IYA OSUN(Osun priest) OPON IFA(Ifa tray) Egungun(Mansqurade)

Odun Eyo(Eyo festival) Arugba osun(Votary maid) Orisa ibeji


IROKE IFA ORI OLOKUN

1. Ò̩ s̩ un Aworo(A priest of an idol)


2. Edì
3. Ifá/Ò̩ runmila
4. O̩batala
5. Ògún
6. S̩àngó
7. O̩ya
8. Ès̩ ù,
9. Sanponna,
10.Orisa Oko
11.Iyemoja
12.Egungun
13.Oro
14.Osanyin
15.Ayelala
16.Gelede

IGBELEWON:

Dárúko̩ awo̩n oris̩ a ilè̩ Yoruba marun-un ti o mò̩ .

ISE ASETILEWA

Se akosile orisa ile yoruba mewaa ti o mo.

IWE ITOKASI;(OYEBAMIJI MUSTAPHA ATI AWON AKO EGBE RE)


(2013:65-78)
OSE KERIN(WEEK 4)

AKORI:GBOLOHUN EDE YORUBA.(SENTENCES)

Gbolohun ni oro tabi akojopo oro ti a fi n gbe ero okan jade.A tun le pe
gbolohun ni ipede ti o kun ti o si ni itumo.O maa n ni oro ise ninu,o si maa n ni
ise ti o n je.Bi apeere: 1.Dide .

2.O ra aso.

3.Nje o ri oyin.

4.Dake.

5.Sare.abbl.

ORISII GBOLOHUN(Types of sentences)

1.Gbolohun Abode(simple sentences):Eyi ni awon gbolohun ti won maa ni eyo


oro ise kan soso.Iru gbolohun bayii kii gun pupo sugbon won maa n ni itumo
kikun.Bi apeere:

a.Bola sun

b.Oluko ti de
d.Bola ti lo oko

e.Ojo n jo

e.Ronke fo ikoko

2.Gbolohun Onibo(complex sentence):Eyi ni gbolohun ti a maa fi n bo tabi ha


ihun gbolohun miiran.Won kii da duro bikose pe a fi won ha gbolohun
miiran.Bi apeere:

a.Bola ti lo ki a to de

b.Kola n jeun lowo nigba ti mo wole.

d.A o ra eja bi a ba dele.

e.Won aja ti o tobi .

3.Gbolohun Alakanpo(Compound sentence):Eyi ni gbolohun ti a maa so po


mo gbolohun miiran, lati so di odidi gbolohun, nipa lilo awon oro asopo
bi:sugbon,amo,si,ati,bee ni,abi/tabi,yala--------tabi.Bi apeere:

a.Oga ko ile sugbon ko ni moto.

b.O lowo pupo amo ko ni iwa.

d.Baba jeun o si yo.

e.O gbo bee ni ko dahun.

4.Gbolohun Ase(Command):Eyi ni gbolohun ti a maa n lo lati pase.Bi apeere:

a.E dide.

b.Dake.

d.Aina maa lo.

e.Gbogbo yin,e jokoo

e.Panumo.
f.Wole

g.Jokoo.

5.Gbolohun Alalaye(Explanatory sentence):Eyi ni 7. Dada nko?

a maa n lo lati fi salaye ohun ti a ri,gbo,tabi ti a mo.Bi apeere:

a.Mo pade Tolu ni ojo lanaa.

b.Oba ti waja

d.Baluu ja ni Eko

e.Aso funfun ni o ra.

6.Gbolohun ibeere(Question):Eyi awon gbolohun ti o maa n ni awon atona


ibeere bii; tani, kini, elo,nje, ki lo, nibo, nko abbl. Bi apeere:

1.Tani o wole wa?

2.Kini o je lana?

3.Elo ni o ra bata naa?

4.Nje won ti jeun?

5.ki lo sele si Kola?

6.Nibo ni aso naa wa?

IGBELEWON.

Iru gbolohun wo lo wa ni isale yii?

i. Ade jeun sugbon ko yo.

ii. Olu ti de ki a to de.

iii. Nibo ni Kola ti n sise?

iv. Sola ti lo oko.

v. Dide.
ISE ASETILEWA

i.Ko gbolohun abode marun-un

IWE ITOKASI:Folarin Olatunbosun(2009:77-82)ETO IRO GIRAMA


YORUBA FUN ILE IWE SEKONDIRI AGBA.

OSE KARUN-UN(WEEK 5)

AKORI:AYOKA ONI-SORO –GBESI(DIALOGUE)

Kola: Awon agba, won ni omokehinde gbegbon Taye gbaburo.

Wunmi: Gbo na, ki ni idi re ti won fi so bee?

Kola: O seun bee laa bi ni , se o ri Taiwo ati Kehinde,iya kan baba kan naa lo bi
won, ojo kan naa ni won si bi won.

Wunmi: Se iyen ni wi pe omokehinde ni won koko bi?

Kola: Fi ara re bale, se o mo wi pe ninu asa Yoruba agba ni o maa n ran omode
nise.

Wunmi: Iyen ti won ba wa lati inu ile kan naa.

Kola:Yala won wa lati ile kan naa tabi otooto, agba ni o n ran omode nise. Gege
bi ohun ti a n so o bo, ni ojo ikunle iya won, eyi ti won koko bi ni a n pe ni
Tayewo nigba ti a n pe eyi keji ni Kehinde.

Wunmi: Kin wa ni idi re gan- an ti eyi tin o kehin de fi di egbon fun eyi ti o
koko de?

Kola: Idi re ni wi pe Yoruba gbagbo pe egbon ni o n ran aburo nise eyi ni o mu


ki Kehinde ran Tayewo wi pe ki o lo to aye wo boya o dun tabi ko dun.
Wunmi:Bawo ni Kehinde naa se wa mo pe aye dun ti oun naa fi n bo?.

Kola: Nigba ti ko ri Tayewo mo ki o wa jise fun-un, ni oun naa ba fi n bo.

Wumi: Se idi niyi ti won fi n pe won ni oosa?

Kola: Awon eniyan n pe won ni oosa nitori pe ibeji ni won ati wi pe ohun ti
eniyan ba se fun ikan ninu won,o gbodo se e fun enikeji naa.

Wumi:Se iya won tun le bi omo le won bi?.

Kola: Beeni , omo ti won ba bi le won ni a pe ni Idowu, eyi ti o ba tele Idowu ni


Alaba eyi ti a bi tele Alaba ni Idogbe ti o si kerin won.

IGBELEWON

Dahun awon ibeere wonyi

1 .Ewo ni ko si ninu oruko iran ibeji ninu awon oruko wonyii?


A. Alaba
B. Idowu
C. Kehinde
D. Kola
E. Idogbe
2 .Kin ni idi re ti omokehinde fi gba egbon lowo Tayewo? Nitori pe
A. Iya kan naa lo bi won.
B. O de kehin.
C. O je obinrin.
D. O je okunrin.
E. Oun lo ran Tayewo nise.

3. Tayewo Kehinde je oosa nitori pe,


A. Baba kan naa lo bi won.
B. Ibeji ni won.
C. Iya kan naa lo bi won.
D. tegbon taburo ni won
E. won feran ara won.
4. Oruko omo ti a koko bi le Taiwo Kehinde ni.
A. Alaba
B. Idowu
C. Idogbe
D. Ibeji
E. Ilori
5. Igbagbo Yoruba ninu ibeji ni wi pe Tayewo ni
A. abekehin
B. aburo
C. aremo
D. egbon
E. omo iranse
ISE ASETILEWA
1. Ewo ni kii se ooto ninu awon gbolohun wonyii?
A. iya awon ibeji le bimo le won
B. iya ibeji ko gbodo bimo le won
C. kehinde ni egbon Tayewo
D. ojo kan naa ko ni a bi Tayewo ati Kehinde
E. omo ti a bi leyin ibeji ni Kehinde

2. Omo ti a bi tele Idowu ni__________

A. Alaba
B. Idowu
C. Idogbe
D. Ilori
E. Taye
3. Omo meloo ni a daruko ninu ayoka yii?
A. meji
B. meta
C. merin
D. marun-un
E. mefa
4. Omo ti a bi tele Alaba ni ______
A. Adewale
B. Kehinde
C. Idogbe
D. Ilori
E. Bola
5. Igbagbo Yoruba gege bi a se ri ninu ayoka yii ni pe________.
A. Aburo ni o n ran egbon nise
B. Aburo ni o maa n se gbogbo ise
C. Egbon ni o maa n ran aburo nise
D. Egbon ni o n se gbogbo ise
E. Iya awon ibeji ko gbodo ran won nise.

OSE KEFA(WEEK 6)
AKORI:AYOKA (COMPREHENSION)

Ka awon ayoka isale yii, ki o si dahun awon ibeere ti o tele won.

Ilu oyinbo dara ni tooto, ko si ole nibe beeni ko si ole, aye derun, iwa jibiti
ko po nibe ati oti amupara beeni eni kookan lo mo eto re, ara idi niyi ti ko fi si
ireje. Ounje ti o dara wa nibe bii ounje inu agolo, eran adiye, tolotolo, maluu, eja
odo, bee gege ni orisiirisii eso igi po nibe, bii eso kasu, osan, ogede, ope oyinbo,
gurofa ati awon miiran.

Bi aye se rorun nibe lati gbe bee ni awon inira naa po to, lara won ni owo
ori sisan, owo ile, owo ina, owo redio, owo omi ati awon ohun elo inu ile miiran.

Inira ti o buru ju nibe ni otutu, ko si aye imele lenu ise, iro pipa ko si beeni ko si
iwe yiyi tabi ojusaaju, enikeni ti o ba ti se, ti owo si tee yoo je iya ti o to sii gege bi
ese re.

IGBELEWON

Dahun awon ibeere wonyi

1. Ilu wo ni a so wi pe o dara ninu akaye yii? Ilu


A. Eko B. Oba C. Oyinbo D. Oyo
2. Gbogbo awon iwa buruku yii ni ko si nibe ayafi
A. iwe yiyi B. Ojusaaju C.ijo jijo D.Oti amupara
3. Iru iya wo ni eni ti o ba se n je nilu Oyinbo?A.Iku B.Jije iya ti o to si ese re
C.fifun ni egba D.Jiju si inu ina
4. Inira wo ni alakaye so pe o buru ju nilu oyinbo
A. Ijiya B.otutu C.oorun D.ofin won
5. Gbogbo awon eran jije wonyi ni a le ri ayafi
A. adiye B.eja odo C.igbin D.folotolo

ISE ASETILEWA
1.Toka si okan lara awon inira ti o wa ni olu oyinbo?
A. aisan owo osise deede B.owo ori sisan C.ebi pipa D.eniyan lilu
2. Kin ni idi re ti ko fi si ireje nibe?A.enikookan mo eto re B.eru olopaa ba
won.C.owo po nibe D.esin ko gba ireje
3. Ewo ni ko si ninu eso igi ti alakaye
menuba ninu akaye re?A.gurofa B.ibepe C.kasu D.osan

4. Orisii owo sisan bii ona meloo ni


alakaye menuba? A. okan B. meji C. marun-un D.merin
5. Gbogbo awon wonyi ni ko si aaye fun lenu ise gege bi o se wa ninu akaye
naa ayafi
A. imele sise B. iro pipa C. iwe yiyi D. pipe debi ise

OSE KEJE(WEEK 7)

ISINMI RANPE(MID TERM BREAK)


OSE KEJO(WEEK 8)
IKINI TI O JEMO ISELE ATI ISE NI ILE YORUBA(Greetings
that has to do with events and occupations)

Asa ikini je okan pataki lara awon asa ile Yoruba.O tumo si
ki a mo riri eniyan,ki a si bu ola fun onitohun.Iwa afojudi gbaa
ni ki omode ri agbalagba,ki o maa ki iru agba bee,ko dara
to.Nitori naa,awon Yoruba ka ikini si pupo .Gbogbo nkan ni ikini
wa fun ni ile Yoruba, a ni ikini fun awon isele,bee si ni a ni awon
ikini fun gbogbo ise abinibi ile yoruba patapata.Bi apeere:

ISELE(EVENTS) IKINI(GREETINGS) IDAHUN(


RESPONS
E)

Aboyun(pregnant E ku ikunra,a so kale anfani Ooo


woman) o,were la o gbo.

Iya olomo tuntun E ku owo lomi,olorun a wo, e Amin o.


(new born baby) ku ewu omo o.

Nibi isomoloruko E ku ijade oni o,Olorun a da Amin o


(naming ceremony) omo naa si.

Eni to sese gbe iyawo Eyin iyawo o ni meni o,e ku Amin o


(New couple) inawo o.

Ibi isile(house Ile a tura o,e ku inawo. Amin


warming)

Ibi isinku agba E ku aseyinde o.eyin Amin o


(burial) baba/mama a dara o.

Eni ofo se A o ni ri iru e mo. Amin.


(sorrowful events)

Ibi isele ayo(joyful E ku orire o. (Congratulation) Ooo, ese.


events)

IKINI TI O NI SE PELU ISE(GREETINGS THAT HAVE TO DO WITH


OCCUPATIONS)

ISE(OCCCUPATIONS) IKINI(GREETINGS) IDAHUN(RESP


ONSE)

Agbe(farmer) Aroko bodun de o O amin .

Alagbede Aroye o Ogun a gbe o.


(blacksmith)
Ode(hunter) A rinpa ogun o,Owo a de o Ogun a gbe o
o.

Onidiri Oju gbooro,e ku ewa. Ooya o ya.


(hair dresser)

Amokoko(potter) Amoye o Iyamopo a gbe


o

Awako(driver) Oko arefo o,a waye o. Amin o

Alaro(tie and dye) Aredu o,arepon o Ase o

Babalawo Aboruboye Aboye bo sise

Apeja(fishermen Owo a de Ase o

Oba(king) Kabiyesi o,Ki ade pe lori,Ki Ase o


bata pe lese

Ahunso(weaver) Ahunya o. Amin o.

IGBELEWON

Bawo wo ni a se n ki awon wonyi:

1.Babalawo

2.Agbe

3.Ode

4.Alaro

5.Awako.

ISE ASETILEWA

Daruko ise ile Yoruba marun, ati bi a se n ki won.


OSE KESAN(WEEK NINE)
AKORI: EBI(FAMILY)

Ebi je akojopo awon eniyan ti won je okan na nipa eje. Okunrin ati
obinrin, omode ati agba ni won je irufe awon eniyan ti a n pe ni
ebi.Gbogbo eniyan patapata labe orun ni won ti inu ebi kan tabi
omiiran jade.Ko si eniti o jabo lati orun tabi lati ori igi,nitori naa,
ibasepo to dan moran gbodo wa laaarin awa ati Ebi wa bi o tiwu ko ri.

Akiyesi fi han wi pe ni ibi gbogbo bii ile, aye ni a ti le ri ebi.


Paapa olukuluku wa lo wa lati ebi kan tabi omiiran.

Orisii Ebi to wa(Types of Family)

1. Ebi kekere (Nuclear family)

2. Ebi to gbooro (Extended family)


1. Ebi Kekere: Eleyi ni ebi ti awon eniyan inu re ko ju baba (olori
ebi), iya ati awon omo won lo.

2. Ebi to gbooro: Eleyi ni ebi to gbooro,ti opolopo eniyan po sibe,o


saba maa n je agbo ile nla.Won a si maa se ohun gbogbo papo
ninu ife.

APEERE EBI KEKERE(Examples of Nuclear family)

Baba=Father

Iya=Mother

Awon omo=Children

APEERE EBI TO GBOORO(NLA)(Examples of Extended family)

Baba-Agba=Grandfather

Iya-Agba=Grandmother

Aburo iya ati baba / tabi egbon iya ati baba (lokunrin) = Uncle

Aburo iya ati baba / tabi egbon iya ati baba (lobinrin) = Aunt

Omo egbon eniyan = Cousin

Omo egbon/aburo obinrin=Niece

Omo egbon/aburo okunrin=Newphew

Omoomo=Grandchildren.abbl.

IGBELEWON
Daruko awon eniyan wonyi ninu ebi ni ede yoruba

1. Nephew =

2. Niece =

3. Great grandfather =

4. Great grandmother =

5.Uncle=

ISE ASETILEWA

Ya aworan Ebi kekere kan sinu iwe ileewo.

OSE KEWAA(WEEK 10)

AKORI:IBEERE ATI IDAHUN.


IBEERE IDAHUN QUESTION ANSWER
1. Ìyá,kí lè n Àkàrà What are you Beans cake
tà? selling?
2. Kí ni o rù? Igbá ni. What do you Calabash
carry?
3. S̩e o jiire? A dupe̩ o Did you wake up Yes, I did.
well?
4. Ki ni oruko̩ Bo̩la What is your Bo̩la
re̩ ? name?
5. S̩e o ti Rárá Have you Yes, I have.
we̩ tan? bathed?
6. Ki lo n Ebi n pa mi. What is I am hungry.
s̩ e o̩? wrong with
you?
7. Níbo ni O lo̩ si o̩ja. Where did He went to
S̩adé lo̩? S̩ade go? the market.
8. Níbo lo Ìbàdàn Where do you Ìbàdàn
n gbé? live?

IGBELEWON

Ki awon akekoo se atunka ibeere ati idahun yii loju patako.

ISE ASETILEWA

1.Kinni Iya n ta?

2.Nibo ni Sade lo?

IWE-ITOKASI(S.Y ADEWOYIN,2013:28-29)SIMPLIFIED YORUBA L2,


7,8,&9).

OSE KOKONLA(WEEK 11)

Atunyewo ise saa yii ati Idanwo(Revision and Examination)

You might also like