Pipe Ogun
Pipe Ogun
Pipe Ogun
esu pipe
Eṣu mo pe ọ
Eṣu mo pe ọ ,
Eṣu mo pe ọ
Laroye mo pe ọ
Laroye mo pe ọ
Laroye mope o
Ti a ba fẹ fi ọ ja Laalu ni orukọ rẹ
To ! Abala Esu
esu pipe
7. Eni Èsù bá n se ki í mò
Concluido el pípè comenzamos con el Ijúbà apropiado , que es longue mas es relativo
a vínculo entre Ìyáàmi Òsòròngà e Èsù, sendo a primeira quien confere libertade de
accion e Àse a Èsù para producir fenómenos. Lembre mesmo stuff de dedos en agua
cada vez que oye Iba:
Ki a to te omi
Ìbà Oganjo
Ìbà Akódá
Ìbà Àsèdá
Tin se Ebora ayé
Ìbà Èsù ni a nda ki a to bo Òrìsà
Mo duró, mo júbà Èsù !!
Mo bere, mo júbà Èsù !!
Mo júbà obìnrin
Mo júbà okùnrin
Mo júbà omodé
Mo júbà àgbàa
Ìbà gbogbo yin kin nto mu awose
Mo wa la tí wa júbà re Èsù alagbára alase omo Èlèdùmarè
Ìbà ni tirè Èsù, Ìwo Elegbára
Eboro olowo ijo
A se òtún
Se òsì
La ni ìtíjú
Èsù Òdàrà je owuro mi o san mi
Èsù Òdàrà je ale mi o san mi
Èsù Òdàrà ti nje latopá
Elépo lénu
Òdàrà tí nje elegbára
A yi kò ndun si éyìn
Eleyin
Okùnrin onà
Okùnrin ogun
Onilè oríta
Agbà òrìsà a sòrò náà di omiran
Laróye o !! Laróye o !!
Omi lero iná
Epo lero Èsù
Ìbà mi náà fún éyìn Ìyámi Òsòròngà
A pa ení ma yo ida
Olókiki oru oko nsise
Orí ilè ni
Ayan e mo náà nko o
Orí ilè náà ni
Elegbara mo júbà re o
Ma je ilè yi o yo
Mo mi lésè o
Agbà da ngbá òhún akara omo Èlèdùmarè
Iwo lo pa oko sinu iná o pa ale si idi aro
O tun wa pa ìyá wo si ehin ilè, Ìbà re o
Ebíta okùnrin ma pa mi
Ma si pa ènìyàn
Simi lórun o
Èsù láàlù mo yilé
Ìbà yin o
Iwo ebora olowo
Mo júbà re o
Oba àwon imalè èni tí kò mo e ni npe e ni onikumo
Èmi ni orígbemileke omo Èsù Òdàrà ki òhún búrúkú o
Parada láyé mi o
Èyín okanleigba ebora inú ayé, Ìbà yin o
Mo tun júbà oganjo tí nse omo ìyá orù olojo
Ìbà !!
Èsù ganranganran
Lebara wa gbo òhún mi o
Ìbà omi ni a nju
Ki a to pa eja
Ìbà igbo ni a nju
Ki a to sóde
Ìbà náà ni a nju
Ki a to pa eye bí omodé bá dé ibi oro la júbà àwon Ìyá Mogun
Àwon Ìyá Mogun pèlú àse Èsù Òdàrà won a fí orí re tèlé apò
Èsù Láàlù mo júbà re o ikoríta méta
Ayé tòun Òrun Ìbà
Éyìn Ayé
E ma da ile mi o nko ni da tí yin náà o ení bá dalè
Ki ilè um lo o
Èsù alase òrìsà òun lo se alakoso wa
Le ti odò odaleberu legbe
Yèyé àti pèrègún omi
Odò náà re o ko tíí gbe o
Yèyé èti odò náà re o ko tíí gbe o
Pèrègún etì odò náà re o ko tíí gbe o
Ewé orí won ko ti wo o
Èsù ma je orí mi
Eledá mi o o sin mi sile o
Mo tun nfibà àwon okanlenigba imalè tí won nse ojise Èlèdùmàrè
Ìbà Èsù láàlù eni tí e ngbá àse lowore
Legbara, Legbara ìràwò akódá tí mo nwo yi ti nse aya ojú Ìbà !!
Èsù Òdàrà ìràwò Akódá
Àse ebo lówó
Binba rúbo nko o
Je ebo mi o dá o
A jebo jeebo mi o dá
A ajebo mo tún júbà Òorun
Èyí tí nse aya
Owuro kutu
Orí mi
Eledá mi
Ìbà re o !!
Igi hu nínú igbo
Orí ilè ni àdá nsise
Orí ilè ni
Mo tun júbà èyín Ìyámi Òsòròngà opiki elésè osun
A jefun jedo
Èsù, ma je àwon ìyá Mogun fi Orí mi tèlé apò ikin le gbo
Bí o gbo nkin tótó ki ojó mi o dale o èyín
Okanlenirinwo imalè náà nko o
Ìbà ni mo nje
Ise ko ni moran yin e mase aí
Kò jé mi o e ma gbàgbé irùkere
Èsù láàlù Ìbà re o
Je ilé ayé
Mi osan mi
Ki o tú ni negénnegén bí omi odò a fi owuro pón o
Èsù òdàràkase nlé ki nribi lo
Èmi lomo aró gidigba tí nbo lónà
Láàlù
Ma joko lè mí
Ki o ma tún joko le omo mi
Èsù okùnrin kukuru tí nbe l'ónà ojà
Èsù láàlù mo júbà re o
Ìbà Ajé o !!!
Ìbà Èsù !!!
Àse.
oriki esu
Osun
kiki osun
iba osun
saudação a osun
reza de ose otura que fala como osun veio para terra
Ogun
bata com o pé esquerdo no chão 3 vezes diante do assento de ogun
PIPE OGUN
sopre unm pouco de oti em ogun e recite
IBA OGUN
depois se verte sobre ogun bastante oti ou emu
Oríkì Ògún
Ògún pèlé o!
Ògún alákáyé,
Osin ímolè.
Ògún alada méjì.
O fi òkan sán oko.
Ofi òkan ye ona.
Ojó Ògún ntòkè bo,
Aso iná ló mu bora,
Ewu eje lówò.
Ògún edun olú irin.
Awònye òrìsà tií bura re sán wònyìnwònyìn.
Ògún onire alagbara.
A mu wodò,
Ògún si la omi Logboogba.
Ògún lo ni aja oun ni a pa aja fun.
Onílé ikú,
Olòdèdè màríwò.
Ògún olónà ola.
Ògún a gbeni ju oko riro lo,
Ogún gbemi o.
Bo o se ghe Akinoro.
Ìjálá Ògún