Peter D. Mitchell
Ìrísí
Peter Dennis Mitchell | |
---|---|
Ọlọ́lá Peter Mitchell, M.P. | |
Ìbí | 29 September 1920 Mitcham, Surrey, England |
Aláìsí | 10 April 1992 | (ọmọ ọdún 71)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | United Kingdom |
Pápá | Biochemistry |
Ibi ẹ̀kọ́ | Jesus College, Cambridge, University of Edinburgh |
Ó gbajúmọ̀ fún | discovery of the mechanism of ATP synthesis |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Chemistry in 1978 |
Peter Dennis Mitchell, FRS (29 September 1920–10 April 1992)[1] je onimo kemistri elemin ara Britani to gba Ebun Nobel fun Kemistri ni 1978 fun iwari re ona isise kemiosmotiki ti idapapo ATP.
Mitchell je bibi ni Mitcham, Surrey, Ilegeesi[2].
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Milton H. Saier Jr. "Peter Mitchell and the Vital Force". Retrieved 2007-03-23.
- ↑ NNDB. "Peter Mitchell Bio at NNDB". Retrieved 2007-03-23.