Nnimmo Bassey
Nnimmo Bassey | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 11 June 1958 Nigeria |
Iṣẹ́ | A Nigeria architect, Environmental activist,An author and a poet. |
Nnimmo Bassey ( a bini ọjọ kọkanla, óṣu June, Ọdun 1958) jẹ ayaworan ilẹ ti Naijiria, ajijagbara fun àyika, onkọwe ati akewi to ṣè agbatẹ̀ru ọrẹ ti ayika agabaye lati ọdun 2008 de 2012[1][2].
Igbèsi Àyè ati Ẹkọ Nnimmo Bassey
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bassey kẹkọ nipa ayaworan ilè to si ṣiṣẹ ijọba fun ọdun mẹwa lẹyin naa lo tẹsiwaju lori iṣẹ aladani nipa aworan ilè. Arakunrin naa jijagbara lori ẹtọ ọmọ eniyan ni ọdun 1980s nibi to ti jẹ Board awọn óludari ti Nigeria Civil Liberties Organization[3].
Ni ọdun 1993, Bassey da awujọ aladani ti oloyinbo mọsi NGO silẹ pẹlu ẹlomiran eyi ti orukọ rẹ jẹ Ọ̀rẹ ti aiye ilẹ Naijiria (Friends of the Earth Nigeria) eyi ti da lari awọn igbèsè lori wiwo ati ṣiṣe atunṣè si idaamu to deba ayika ẹtọ ọmọ eniyan ni órilẹ ede Naijiria[4][5]
Lati ọdun 1996, Bassey ati igbèsẹ ẹtọ ayika dari Oil watch ilẹ Afrika, ni ọdun 2006, Bassey dari Global South Network, Oil watch ti àgbaye lati lodi titan rirọ fossil fuels jade ni agbègbè. Bassey ti ṣiṣẹ labi ajọ ti Oil watch ilẹ Afrika ati ti àgbaye[6][7].
Ìṣẹ Nnimmo Bassey
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Bassey dari Ọrẹ Ayika agbaye lati ọdun 2008 de 2012 fun ọdun mẹwa lọna mèji, oludari igbèsẹ lori ẹto ayika. Arakunrin naa jẹ oludari ilera ti Mother Earth Foundation[8][9]. Bassey ti ṣiṣẹ pẹlu To Cook a Continent: Destructive Extraction ati Idààmu oju ọjọ ni ilẹ Afrika[10].
Ẹyẹ ati idanimọ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Akọni Àyika Time Magazine ni ọdun 2009[11]
- Olugba Àmi ẹyẹ Laureate Right Livelihood ti ọdun 2010[12].
- Olugba ẹbun Rafto ti ọdun 2012[13]
Awọn itọkasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Nnimmo Bassey". rightlivelihood.org. 2010-11-30. Archived from the original on 2014-04-22. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Oil politics : echoes of ecological wars in SearchWorks catalog". SearchWorks catalog. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ Ugochukwu, Nnaemeka (2020-03-10). "7 Top African Environmental and Climate Activists Fighting for a Sustainable Future". Eco Warrior Princess. Archived from the original on 2023-09-29. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Nnimmo Bassey elected chair of Friends of the Earth International". Home. 2010-11-22. Archived from the original on 2010-11-22. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Nnimmo Bassey Biography". Friends of the Earth International. Archived from the original on 13 April 2013. Retrieved 22 March 2014.
- ↑ "Environmental Rights Action". ERA. 1993-01-11. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Oilwatch in Africa". Oilwatch. 2023-08-23. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Health of Mother Earth Foundation". Retrieved February 11, 2014.
- ↑ "We Need to Overturn the System". Health of Mother Earth Foundation. Archived from the original on 3 March 2016. Retrieved 22 March 2014.
- ↑ Resources, Trainings. "To cook a continent. Destructive extraction and the climate crisis in Africa". Pambazuka Press;several African countries. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Heroes of the Environment 2009". TIME.com. 2009-09-22. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ "Nnimmo Bassey". Right Livelihood. 2021-08-10. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ «Raftoprisen til Nnimmo Bassey», Vårt Land, 27. september 2012.
- ↑ Bankole, Idowu (2019-07-23). "Nnimmo Bassey bags York varsity honorary degree". Vanguard News. Retrieved 2023-09-03.
- ↑ Nigeria, Guardian (2019-07-28). "Bassey bags University Of York’s doctoral award". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Archived from the original on 2023-09-03. Retrieved 2023-09-03.