Mark Zuckerberg
Ìrísí
Mark Elliot Zuckerberg tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrìnlá oṣù karùn-ún ọdún 1984 (14 May 1984) jẹ́ oníṣòwò ayélujára, afọwọ́ṣàánú àti ọ̀kan lára olùdásílẹ̀ àti Aláṣẹ yánányán ìkànnì abánidọ́rẹ̀ẹ́, Facebook ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. [1] [2] [3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Mark Zuckerberg". Forbes. 2019-08-14. Retrieved 2020-01-09.
- ↑ "DEF 14A". SEC.gov. 2013-04-23. Retrieved 2020-01-09.
- ↑ "Facebook Surges and Mark Zuckerberg Pockets $3.8 Billion". Yahoo Finance. 2018-08-26. Retrieved 2020-01-09.
- ↑ "Facebook shareholders are wedded to the whims of Mark Zuckerberg". Los Angeles Times. 2017-12-02. Archived from the original on 2017-12-02. Retrieved 2020-01-09. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)