Jump to content

George Eliot

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
George Eliot
Aged 30 by the Swiss artist Alexandre Louis François d'Albert Durade (1804–86)
Resting placeHighgate Cemetery (East), Highgate, London
Pen nameGeorge Eliot
Iṣẹ́Novelist
ÌgbàVictorian
Notable worksThe Mill on the Floss (1860), Silas Marner (1861), Middlemarch (1871–72), Daniel Deronda (1876)
SpouseJohn Cross (m. 1880)
PartnerGeorge Henry Lewes (lived together 1854–1878)
RelativesRobert Evans and Christiana Pearson (parents); Christiana, Isaac, Robert, and Fanny (siblings)

Mary Anne (Mary Ann, Marian) Evans (22 November 1819 – 22 December 1880), daada pelu oruko ikowe re George Eliot, je alakodun ara Ilegeesi, oniroyin ati ayedepada, ati ikan ninu awon olukowe asiwaju igba Ffiktoria. O ko akodun meji, ninu won ni The Mill on the Floss (1860), Silas Marner (1861), Middlemarch (1871–72), ati Daniel Deronda (1876), opo won da lori igberiko Ilegeesi, won si gbajumo fun iseonigidi ati ifojuwo inuokan won.