Jump to content

Adebayo Adefarati

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Adebáyò Adéfaratì (February 14, 1931[1] – March 29 2007) je oloselu ara orile-ede Naijiria ati Gómínà Ìpínlẹ̀ Òndó tele. Adefarati kú ní ojokandinlogbòn osù kéta odún 2007.


  1. "Adefarati, AD Presidential candidate dies at 76" Archived 2007-10-13 at the Wayback Machine., Vanguard (Nigeria), March 30, 2007.