Aarhus
Ìrísí
Århus | |
---|---|
Århus inner city in 1998, from the South Harbor side | |
Country | Denmark |
Region | Central Denmark Region |
Municipality | Aarhus Municipality |
Area | |
• Urban | 91 km2 (35 sq mi) |
• Metro | 9,997 km2 (3,860 sq mi) |
• Municipal | 468 km2 (181 sq mi) |
Population | |
• Urban | 242.914 |
• Urban density | 2,636/km2 (6,830/sq mi) |
• Metro | 1,228,398 (17 municipalities in East Jutland metropolitan area) |
• Metro density | 123/km2 (320/sq mi) |
• Municipal | 307,119 |
• Municipal density | 656/km2 (1,700/sq mi) |
Time zone | UTC+1 (Central Europe Time) |
• Summer (DST) | UTC+2 |
Aarhus, tabi Århus (Àdàkọ:IPA-da), ni ilu titobijulo keji ni orile-ede Denmark, ilu titobijulo 99run ni Isokan Europe, ati ikefa-titobijulo ni arin awon orile-ede Nordiki. Gege bi ebute pataki ile Denmark, o budo si egbe ilaorun peninsula Jutland ni gbongan onijeografi ile Denmark.
Ìlú tó tóbii sèkejì ní ilè Denmark. Àwon okò ojú omi máa n gúlè sí ibè. Ó ní Yunifásítì kan. Àwon ènìyàn tí ó wà níbè ní 1955 jé 118, 943. Òun ni olú-ìlú A.Co ní Jutland.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 "Vision Østjylland", Miljøministeriet, 20. august 2008 Àdàkọ:Dk icon, a describtion of the East Jutland metropolitan area
- ↑ BEF44: Population 1st January, by urban areas database from Statistics Denmark