Ìrẹsì
Ìrísí
Ìrẹsì jẹ́ èso irúgbìn ohun ọ̀gbìn tí gbogbo ènìyàn ma ń jẹ jákè-jádò orílẹ̀ àgbáyé, pàá paa jùlọ ní ilẹ̀ Asia. Ohun ọ̀gbìn yí jẹ́ ọ̀kan gbòógì nínú ohun ọ̀gbìn óúnjẹ tí wọ́n pèsè jùlọ ní àgbáye ní iye ( 741.5 mílíọ́nù tọ́ọ̀nù ní ọdún 2014), lẹ́yìn Ìrèké àti àgbàdo.
Nígbà tí wọ́n ma ń lo ìrèké àti àgbàdo fún ìpèsè oríṣríṣi nkan, yàtọ̀ sí jíjẹ lásán bíi ti ìrẹsì.
[1] Oríṣríṣi ìrẹsì ló wà, irúfẹ́ èyí tí ó bá hù ní agbègbè kan ma ń dá lórí ilẹ̀ àti ojú ọjọ́ agbègbè náà.
.[2]
Àwọn Ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Smith, Bruce D. (1998) The Emergence of Agriculture. Scientific American Library, A Division of HPHLP, New York, ISBN 0-7167-6030-4.
- ↑ "The Rice Plant and How it Grows". International Rice Research Institute. Archived from the original on January 6, 2009.