Novel
Novel
Novel
SearchSearch
Date uploaded
on Nov 10, 2022
236 views
119 pages
Document Information
click to expand document information
Date uploaded
Nov 10, 2022
Original Title
Attachment(1)23566
Copyright
© © All Rights Reserved
Available Formats
DOC, PDF, TXT or read online from Scribd
Copy Link
Copy Link
Did you find this document useful?
0%0% found this document not useful, Mark this document as not useful
Is this content inappropriate?
Report this Document
Download now
1. TI ABA FE S
E ESUTewe
tegbo ogbo,
ewe aharagbaa,
ewe ina pupa a
funfun, ewe
esisi funf un,
ewe oloyin, ewe
abamoda, ewe
rere,
ewe sawerepep
e,sise re-ao lo
wa yangi
tobawa ninu
odo, ao wa ko
gbogbo awon
ewe yen sinu
ike nla kan, ao
wa ma gbo ara
yangi na ninu
ike gbogbo
ewe yen ma run
mo yangi lara
tan patapata,
ao wa lo ra
isasuntuntun
nla kan, ao wa
iyereosun te
ifa otura lotun-
owonrin losi si
isale isasun na,
ao wa gbe
igbinagbonu nla
kan le ifa na, ao
gbe ori ako aja
kan le ori igbin
na, ao wa ko
gbogbo ewe to
ku owa ninu
ikeyen le ori
ako aja yen, ao
sese wa gbe
yangi yen le
lori, ao wa lo
gun ose dudu a
amo papo, ao
mo eisasun
yen yipo yangi
yen koni le kan
e isasun yen
abi kan ara
isasun
yen,yangi yen
ma wa larin,
aotun wa
iyere-osun te
ifa otura lotun-
owonrin losi le
yangi na loke
pata pata, ao
wa ta epo le
lori, aoma se
nkan taba fe,
ao ma pa akuko
adie le lori
2. OGUN O
WO GBEW
A TODAJU.
Ajiyo tutu
toni oruko
amo oruko
iyare, aowa
gbogbo owo
won naa ni
oriledeaiye
eyitoba
wuwa bi
dollars ,
pound
sterlin, Yen,
Dinnar,
cever pelu
owo totobij
ulo ni orile
ede aba
se iseyi.
Aowako
gbogbo
awon owo yi
senu ajiyo
yi aoko
eweomonigel
egele lelori,
aoko ewe
ola
tutu lelori ,
aogbe ori
obo kan
lelori, aogbe
omo
abifohun
abiku kan
lelori, ao
ikode mesan
lelori aoko
owo eyo 201
leloriao
white
makuri tele
pelu
odidi atare
mesan
aodepa ninu
koko tun
totobi.Aowa
lo ra posi
cun tun
kan aowa
gbe sinu re
fun ojometa
ni ojo
saturday
nisise re
asi gbudo
jo ni ojo
monday osi
gbudo
gbewa ni ojo
thur. Tia
bawa
gbesinu posi
tan aowa
asofunfun
po aoda
sasorabia a
bintu
original
lelori
ninunposi
aolo sin sinu
boji oku
cementry
oku po nibe
dada koba
se inu igbo
ni
ojosaturday
12pm.
Tiobadi ojo
monday
12pm aolohu
pada. Mo
olohun bura
abawu
posi naa
makun
fun owo
bundle 201
oririsi owo
inu akosibe
. Aoko owo
naaaowa lo
ko ilenla
sinu
igbokan aow
a ko ibikan
laarin 21
days
agbudo
kotan.Akiye
si akogbodo
naa nibi owo
naaoo
agbudo
kole
fun nioo. Tio
badi ojo
kokanlelogu
n aolo hu
posinaa
laisiwo aowa
lobomo
inu yarakan
ninunn ile
a kofun.
Nioru
ojonaa
laotun siwo
laoto sese
mako owo
towa nibe
se
ohun rere.
Eewo renipe
aogbodo
owo kan oku
nijo
abadanwo
ijona ni iku
de. Ekeji
akogbudoso
wo motor
rira tabi ta
sugbon
alera funyan
kosentoban
wu. Eketa
akogbudoba
yan jenpapo
ninun
abokan
nijoabadan
wo ni eninan
yioku. Leyin
eleyi koni
Trusted by over 1 million members
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
eewo kankan
mo
odamiloju
obarimi
mahan ninu
ilemi
ninu igbo.
Fun
ekunrereala
ye iwo
obafe
sorire
nikan nikiop
emio aijebe
olewu3. Osh
ole taraa ak
eesuibi
ewure o
bi ibeji,opa
aso funfun
kan,ewe ailu
201,ewe
abamoda
201,ewealup
aida 201,obi
in 201,obi
ipa 201
atare
201,ao ko
gbogbo re
sinu aso
funfun,ibiew
ure yen nia
tele ao wa
to gbogbo
awon eroja
yoku tele
rawon ao wa
aboewure
ko gun ri
ao so mole
tobadi ago
mefa irole
ao po ogun
yi mo eri
eko yio je
tobadi ago
mefa irole
lojo keji ao
pa eran na
ao ba ao ba
aso funfun
ninu reao se
gbe dada ao
wa apo
iroko
kekere ao
aso na sinu
apo na ao
ko owo
ada loko yi
leleri ao
loma ko owo
ninu apo na
lojojumo:NB
ojo aba
kuna la
muowo ninu
apo yen
obaje niyen
o,Ako gbodo
mu owo a
da
lokowo4. OK
UNRIN TI
OLORI OBI
RIN A o wa
ori okere
abo awo
ekun die oju
oro osibata
aolowon
papo
aodasinulon
da bintu
aomansara
jade walai
awon obirin
daran
texted
nd confrm5.
APE TI AFI
PE ENIA PA
DA----------
--------------
-----Igbin
kekere to
gbonu 1
ewe sawere
pepe ewe
werepe ao
gun papo ao
po loseaoko
sinu ike
funfun ao
ma omi
gbigbona
we,OFORE:-
Igbin tose
ehin bebere
toko ehin si
orisa,to
lohun koba
orisa se mo
atenuataya
loma gbo le
be
orisa.gbogb
o omira mi
to ni ohun
ko ni wa
bami
semo.sawer
epepe ko lo
ba mi pe
won wa6. O
SOLE 1m
To ba ni ebe
pelu imule
gidi Lara
kotodi ojo
mokanla o
gbudo ri
owo yen
GBAkope
iye yen.
{Sugbon
pelu
ebe&imule
tokajue
ni fah}Oga
aaye kan, ao
Taadah ko
zero meta
kun
zero towa
Lara
1000naira
tuntun,aowa
we owo yen
bi siga
mimu,ao ko
eso iranje
pelu irun
iyamopo
sinu e, ao
kiibooga yen
lenu,ao GBE
sinu ape,ao
odidi
atare aja
kan
si legbe.ao
wa ewe
iranjemokan
la bo...odi
jijo.ao lo
kuna
DadaLilo-
re:--------
Ao omi
agbon odidi
lo lekanna ni
1:00am ni
ihoho
omoluabi
pelugbolohu
n
yi.OHUN:---
--Ihoho
nimowaiye,o
mo araiye
loda aso
asiri bomi.o
ga kiibosi
aarin
ojakomari
e mun,ki
asiri emi l
omo l bo
ju tegbemi
lo
loni.Obinrin
kiito,koma
obohanle,ki
asiri emi l
omo l bo ju
tegbemi
lo.Akiije
owo(money)
kama ri owo
na.emi lomo
l je 1m
loni o.ki
teru-
tomo,tolowo
-toloro
kiiwon wa
bami San
gbese
re.ihohonim
owa,ewa
daso asiri
bomi ooo.
(Adua)Ao
wa da
senu lekann
a, ao omi
agbon lo.ao
lo sun
pada.aso
funfun
laoma
borasun fun
11days
yen.Ao lo
agbon yen
se Sara ni
o.Leyin ojo
kokanla
yen,ao lo ju
aso yen nu
sinu
Igbo8. OGU
NKI OBINR
IN MA LE L
OYUN LE O
MO OWO.O
polopo Awon
obinrin
isiyin lo
kan agbako
latari
gbigba
abere,
tablet a
awonnkan
miran fun
family
planning
awon
oyinbo,
Elomi le ma
ri nkan Osu
e mo tabi
kitelomi ma
ya ni gbogbo
igba, elomi
le ma sanra
tabi ki elomi
ma gbe bi
eni to
koArun a
bebeeeee
lo. Eyi lo wa
mumi asiri
kekere
yi sita fun
afani eyin
Omo
iyami.Ohun
re: Leyin
Obinrin ba
Bi Omo tan,
Eje ibi didi
(Eje o di
si ara aso
o robi)die
Ao di sinu
Lailonu dudu
kekere kan,
ao ta ni
koko dada,
ao lo ran
lawo dudu,
ao so Onde
na mo Omo
ikoko na
lorun owo
Otan. Eyin
Eyan mi
niwonba
Igba Onde
yi ba si wa
lorun owo
Omo yi, Iya
re o le ni
Oyun
le lailai.
Hmmm Mo
gbedifun
gbogbo eyin
Ajuni lo
Aiye pata
pata
ooo9. OGUN
AKOYA AG
BA TO DAJ
U OPOLOP
O
OBINRIN
ODE ONI
NI WON
YON
AGBERE
LAYO ATI
LATI LU
OKUNRIN
NIJIBITI
TI WON SI
NI FE
OKINRIN
NA.
ENIKENI
TI IRU EYI
BA SELE SI
TI O SI FE
KOYAKI O
DAN ISE
YI WO.
ASASI
OBIRIN:AO
KAN AKO
ALANGBA
OYE KAN
MO
ARA IGI
OSE PELU
ESO, AO
FILE TI
O KU
TITITI O
FI JERA
MO ARA
IGI NA
TAN, TI O
BA JERA
TAN, AO
PA EPO IGI
OJU IBI TI
OJERA SI
NA, AO SA
TI O GBE
DADA, TI
O BA GBE
TAN AO LO
TI O
KUNNA
DADA.OBI
NRIN
KOBINRIN
TI ABA
FUN NI
OGUN YI
JE, YI O
MARI ORI
AKO
ALANGBA
LOJUARA
RE TOBA
FE TO
TABI TI O
BA FE
SUNMO
OKUNRIN.
ERO-RE:
AO PA OJU
KEJI EPO
ARA IGI
NA, AO SA
TI O GBE
DADA, AO
LO TI
OKUNNA
DADA, AO
FUN
OBINRIN
NA JE.
OTAN.10. O
GUN IKIYA
FUN OJO
OKUNRIN
TABI OBIN
RINA o wa
egbo
lapalapa
funfun, ota
inu iroko,
odidi atare
kan aojo
papoaoma
busi enu ao
mon mun
omisi tabi
ifoko
mun11. EGB
A KI E DAN
WOE lo
efun ki o
kunna dada,
ki e da sinu
opon ifa
tabi awo
funfun
petere kan,
ki e teni
ODU IFA
merindinlog
un. N.B: bi e
ba te ifa
kan, eo ta
o die sile
lapa otun,
eotun ta omi
lasan die
sile lapa osi,
be le o se
e o te odu
ifa 16 na
tan.LILO
RE:-1- fun
onisowo, e
bu die ninu
oogun yi
sinu ibi e n
ko owo si,
niwonbaigba
oogun yi
bawa ninu
igba owo yin
agbana oni
le wo
inu owo yin
lailai
laseEdumar
e. Koda ele
di ogun yi
sinu iwe
funfun
kekere kan
ki e di ni ra
pelu owufun
fun
nikan. 2- OS
E EYONU ta
bi IPARA E
YONU
Trusted by over 1 million members
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Trusted by over 1 million members
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Trusted by over 1 million members
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Start Free Trial
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Try Scribd FREE for 30 days to access over 125 million titles without ads or interruptions!
Cancel Anytime.
Magazines
Podcasts
Sheet music
Footer menu
Back to top
About
About Scribd
Press
Our blog
Join our team!
Contact us
Invite friends
Gifts
Scribd for enterprise
Legal
Terms
Privacy
Copyright
Cookie Preferences
Do not sell or share my personal information
Support
Help / FAQ
Accessibility
Purchase help
AdChoices
Publishers
Social
InstagramInstagram
TwitterTwitter
FacebookFacebook
PinterestPinterest
Get our free apps
Books
Audiobooks
Magazines
Podcasts
Sheet music
Documents
Snapshots
Language:
English
What is Scribd?
Collapse section What is Scribd?
Quick navigation
Home
Books
Audiobooks
Documents
, active