Oriki 23
Oriki 23
Oriki 23
Revisão
lyakemi Ribeiro
Francisco José Penteado dos Santos
Diagramação e composição
Leonardo van
Halsetna lyakemi
Ribeiro
Sàláml, Sflcírü.
Cânticos dos orixás na África / Sfkírú Sàláml
(King). — São Paulo: Editora Oduduwa, 1991.
1991
Editora Oduduwa Ltda.
Caixa Postal 9301 - CEP 01051
Tel.:(011) 62 9256
São Paulo - Brasil
PREFACIO
Orixá Okô:
Introdução
Ògún onílé ku
Ògún ma se wa lu iku
Má se wá lu ènìyàn
Má se ènìyàn lù wá
Èsù fi ire bò wá o
Elà fi ire bò wá yà yà
Èsù gbé ire ajé kò wá o
Iyá-mògún fi ire bò wá o
Okunrin ònà
Kí o dé ibi
Ki o si ire sílè báyì o.
O homem do caminho,
Que você afaste o mal
E abra caminho para o bem.
Incluímos Egungun, Gèlèdé e Ìròkò entre
os vinte e um orixás. Egúngún e Gèlèdé
constituem respectivamente, culto aos ancestrais
masculinos e ao poder ancestral feminino. Iroko é
a expressão de um fenômeno da natureza a
árvore. No Brasil nos defrontamos com uma
dúvida a respeito do fato de Egúngún e Gèlèdé
serem orixás ou não. Queremos relatar que na
África, entre os yorubás, ambos são considerados
orixás e constituem muitas vezes, o principal
objeto de culto em algumas famílias, como
evidencia a expressão Egúngún ni oro ìle wa, que
significa Egúngún é o orixá cultuado em nossa
família. A mesma expressão é utilizada para
referências feitas aos cultos de outros orixás:
Òbàtàlá ni oro ìle wa, que significa Òbàtàlá é o
orixá cultuado em nossa família, ou ainda Gèlèdé
ni oro ìle wa, Gèlèdé é o orixá cultuado em nossa
família. Outro dado comprobatório do fato de
Egúngún estar entre os orixás cultuados nas
várias famílias são os nomes ou sobrenomes de
algumas pessoas:
A B D E E F G GB H I J K L M N O O P R S S T U
WY
Cuja pronúncia é:
Bàbálòrìsà: A se, a se o,
Égbè: Ase fún o.
Èsù láàlú,
Okírì òkò
Ebìtà okunrín,
A bá ni wóràn,
Bí à ò ri dá,
Olópa elédùnmarè laelae.
O sán sòkòtò pénpé,
Oníbodè Olórun.
O sùn nílé fogo ti kun.
Èsù ló jí.
Ogo kò jí.
Ebora tí njé Látopa.
O bá elékun sunkún,
Kérù ó ba elékún,
Elékún n súnkún,
Láaróyè n sun eje.
O bá onímímí mí,
Kérù ó ba onímímí.
Onímímí n fimú mí,
Láróyè n fi gbogbo ara mí bí Àjére,
Èsù má se mí, omo elòmírán ni o se,
Nítorí eni Èsù bá nse kí í mó,
Bí o bá fi ohun, tirè sílè,
Ohun olóhun nii maa wá kirí.
Èsù Òdàrà,
Orí mí kò ní jé kí èmí rí ìbínú re.
Exu Láàlú,
Okiri òkò,
Ebità Okünrin,
Exu, que causa problemas ao homem
quando o homem não tem problemas.
Ò inspetor de Eledumare, desde o princípio dos
tempos.
Exu amarrou um pedaço de pano na cintura.
O porteiro de Eledumare.
Ele dorme em casa e tranca a porta com seu
porrete.
É Exu que acordou.
Seu porrete não acordou.
O venerável que é chamado Látopa.
Ele, que chora com a vítima
até o ponto da vítima se amedrontar.
A vítima está derramando lágrimas,
Láaróyè está derramando sangue.
Ele que respira junto com a vítima até o ponto da
vítima se amedrontar.
A vítima está respirando pelas narinas
Láaróyè está respirando pelo corpo inteiro, como
uma peneira.
Exu não me conduza ao mal, conduza ao mal
meus inimigos
Pois quem estiver sendo conduzido ao mal por
Exu, não sabe.
Quando ele deixa sua propriedade
vai atrás da propriedade dos outros.
Exu Òdàrà,
Meu orí não vai permitir que eu experimente sua
fúria.
Irúnmalè e se ojú dê o.
Oro, òrò nlo o, òrò,
Igba imalè e se ojú dê o.
Oro, òrò nlo o, òrò.
Osó ilé e se ojú dé o.
Oro, òrò nlo o, òrò.
Aje ilé e se ojú dé o,
Oro, òrò nlo o, òrò.
Olóògún ikà e se ojú dé o,
Oro, òrò nlo o, òrò.
Abínú eni e se ojú dé o,
Oro, òrò nlo o, òrò.
Aba tenijé e se ojú dé o,
Oro, òrò nlo o, òrò.
Gbogbo ibi e se ojú dé o,
Oro, òrò nlo o, òrò.
Gbogbo yín e paradà,
ebo, ebo nbo o, ebo.
Orín Èsù(2)
Èsù bò wá ba wa ré ìkóríta,
Èsù bò wá ba wa ré ìkóríta,
Èsù bò wá ba wa ré ìkóríta,.
Èsù gbà.
A gbé ebó ré ìkóríta,
Èsù gba o.
Légbàrà a gbé ebó ré ìkóríta,
Èsù gbà.
A gbé ebó ré ìkóríta
Èsù gbà.
Oba ló ni òpó
Èsù òdàrà ló ni ìkóríta méta,
Èsù gbà,
A gbé ebó re ìkóríta
Èsù gbà.
Je a mú àse bo ìkóríta,
Èsù gbà. Je a mú àse bo ìkóríta
Èsù gbà,
Èsù gbà. Je a mu ase bo ìkóríta o,
Èsù gbà.
Èsù fi ire bò wá o.
Ela fi ire bò wá yà yà.
Èsù gbé ire ajé kò wá o.
Elà fi ire bò w á y à y à.
lyá-mògún f i ire bò wá o.
Elà fi ire bò wá yà yà.
Ògún pèlé o!
Ògún alákáyé,
Osin ímolè.
Ògún alada méjì.
O fi òkan sán oko.
Ofi òkan ye ona.
Ojó Ògún ntòkè bo,
Aso iná ló mu bora,
Ewu eje lówò.
Ògún edun olú irin.
Awònye òrìsà tií bura re sán wònyìnwònyìn.
Ògún onire alagbara.
A mu wodò,
Ògún si la omi Logboogba.
Ògún lo ni aja oun ni a pa aja fun.
Onílé ikú,
Olòdèdè màríwò.
Ògún olónà ola.
Ògún a gbeni ju oko riro lo,
Ogún gbemi o.
Bo o se ghe Akinoro.
Ogum, eu te saúdo!
Ogum, senhor do universo,
líder dos orixás.
Ogum, dono de dois facões,
usou um deles para preparar a horta
e o outro para abrir caminho.
No dia em que Ogum vinha da montanha
ao invés de roupa usou fogo para se cobrir.
E vestiu roupa de sangue.
Ogum, a divindade do ferro.
Orixá poderoso, que se morde inúmeras vezes.
Ogún Onire, o poderoso.
O levamos para dentro do rio e ele, com seu facão,
partiu as águas em duas partes iguais.
Ogum é dono dos cães e para ele os sacrificamos.
Ogum, senhor da morada da morte, o interior de
sua casa é enfeitado com màríwò.
Ogum, senhor do caminho da prosperidade.
Ogum, é mais proveitoso ao homem cultuá-lo do
que sair para plantar.
Ogum, apoie-me do mesmo modo que apoiou
Akinoro.
Orin Ògún (l)
Ogún yè è.
E má wípé,
Eran lekùn nje.
Eran lekùn nje o.
Ògún ma dekùn.
Eran lògún nje o.
Kini Ogún nje?
Eran lògun nje o.
Bàbálòrìsà: Ta ló lòde?
Talo Iode o?
Égbè: Ògún ló lòde o. Ògún ló lòde.
Bàbálòrìsà: Ògún ló lòde o. Ògún méjèje.
Égbè: Ògún méje ïbà. Ògún méje o.
Ògún méje ïbà.
Àdúrà Ògún
Reza de Ogum
Ìjálá Ògún
Òrúnmìlà Ajànà.
Ifá olókun,
A sòrò dayò,
Elri ìpín,
Ibíkejì Olódùmaré.
Òrúnmìlà akéré finú sogbán.
A gbáyé gbórun.
Olóre mi àjíkí.
Okitìbírí tí npa ojó ikú dà.
Opìtàn Ifè.
Òrúnmìlà o jíre lóni,
tide tide.
Òrúnmìlà o jíre lóni,
Bi olóta ti njí nílé Aró.
Ewi nle Ado.
Ká mò é ká là.
Ká mò é ká má tètè kú.
Okúnrín dúdú òkè ìgbètì.
Òrúnmìlà ò jíre o.
Ifá ìwo ni ará iwájú.
Ifá ìwo ni èrò ìkehìn.
Ará iwájú naa ló kó, erò ïkehìn l’ógbón.
Ifá pèlé o,
Okùnrin Àgbonmìrègún.
Oluwo àgbáyé.
Ifá a mo òní mo òla,
A rí ìhín rí òhún,
Bí oba Èdùmàrè
Òrúnmìlà tíí mo oyún inú ìgbín.
Ifá pèlé o, Erigi a bo la.
Ifá pèlé o, Ókùnrin dúdú òkè ìgbètì.
Ifá pèlé o, Meretelu.
Nibi ti ojúmó rere ti nmó wa.
Ifá pèlé o, omo Enire.
Iwo ni eni nlá mi
Olooto Ayé.
Ifá pèlé o, omo Enire.
Tí nmú ara ògidán le.
Oyín torí omo rè.
Ó sá wo inú kókó igi.
Edé fírífírí torí omo ré,
O sá gun òkè àjà.
Òrúnmìlà tí orí mi fo ire.
Òrúnmìlà ta mí lóre.
A gbeni bí orí eni.
A jé ju òògùn lo,
A mo òní mo òla.
Ifá o jíre lóni o.
Ojúmo rere ni ó mó ojó.
Ifá ojúmó tí o mò yi,
Jè kí ó sàn mí s'ówó,
Jè kí ó sàn mí s’ówó,
Ojúmó tí ó mó yii.
Jé ó sàn mí si àìkú.
Òrúnmìlà ìbà o o.
Oríki (Evocação) de Ifá
(recitada no momento do jogo, para que Ifá
oriente o adivinho)
Òrúnmìlà Ajànà.
Ifá Olókun, que faz o sofrimento tornar-se alegria.
O testemunho do destino.
O vice do pré-existente.
Òrúnmìlà, homem pequeno, que usa o próprio
interior
como fonte de sabedoria.
Que vive no mundo visível e no invisível.
O meu benfeitor, a ser louvado pela manhã.
O poderoso que protela o dia da morte.
O historiador da cidade de Ifé.
Òrúnmìlà, você acordou bem hoje?
Com ide.
Òrúnmìlà, você acordou bem hoje?
Da mesma forma que Olóta acorda na casa de
Aró,
assim louvo suas origens em Ado.
Quem o conhece está salvo.
Quem o conhece não sofrerá morte prematura.
O homem baixo do morro Igbeti.
Òrúnmìlà, você acordou bem?
Ifá, você é a pessoa de frente
Ifá, você é a pessoa de trás
É quem vai na frente que ensina a sabedoria aos
que
vêm atrás.
Ifá, saudações!
O homem chamado Àgbonmirègún,
OIúwo do universo.
Ifá, que sabe sobre o hoje e o amanhã.
Que vê tudo, que está aqui e acolá, como rei
imortal (Edùnmàrè).
Òrúnmìlà, graças a seus muitos conhecimentos, é
você quem sabe a respeito da gestação do igbin.
Ifá, saudações!
Erigi a bo la, que ao ser venerado, traz a sorte.
Saudações a ti, homem baixo do morro Igbeti.
Ifá, saudações a ti meretelu.
De onde vem o sol.
De onde vem o melhor dia para a humanidade.
Ifá, saudações!
Você é o meu grande protetor.
Orin Ifá
Òkété o.
Báyi nìwà re o,
O ba Ifá mulè.
O da Ifá
Ó okété,
Assim é seu comportamento.
Você jurou perante Ifá, não trair-lo.
Você o traiu.
Ó okété,
Assim é seu comportamento.
Você jurou perante Ifá, não trair-lo
Você o traiu.
Orin Ifá (2)
Esò, èsò
Ni ìgbín mà ngun igi o,
Ìgbín kò lówó o,
Ìgbín kò lese,
Esò, èsò
Ni ìgbín mà ngun igi o.
Oríkì Obàtálá
Obàtálá, Obàtarìsà.
Àdàgbà je ìgbín.
O so eni kan digba ènìyàn.
Eni aláyélúwà.
Odúú baba ìkòkò.
Oyígíyigì òtá omi.
Oliwa yo sensen
Orééréé ti ndu orí elemere,
O so àgàn dolómo
Orere ti ndu ori elemere,
O yí láàlà,
O sun láàlà,
O se koko ala rumo rumo.
Oba yigbo.
Eleni a yin.
Oba totó, babá ò!
Obàtálá, Obàtarìsà,
o velho cuja comida preferida é o igbin,
faz uma pessoa se reproduzir em muitas.
A você pertence o universo e o comportamento
dos
seres.
Aquele que moldou todas as crianças. É imóvel
como uma pedra no fundo da água. Oliwa yo
sensen.
A divindade que se preocupa em proteger o orí de
Elemere.
Odùduà
Odùdúà iba.
Bàbá mi a dá ìwa.
Odúà, a mu ìwa gun.
Olóotu ife.
Jagun -jagun, a jí wò oju ojó.
Bàbá mi jí lòwúrò kùtùkùtù.
O be e,yeriyeri.
Lòde Ife.
Oloóre ti ki nje ebi o pá eni.
Olórò, a pórò senu omo èdá.
A da èbi, da àre.
Aláse Ife.
Odúà.
A jagun ségun,
O gbo gbaa-ibon lojú ogun, kó saa.
Odùdúà o f uru bi oyé lóke,
O jagun o ko erú.
Òrìsà eni nwá ire.
Aláse, a wí be se be.
A ro be rí be.
Olóogun gbege.
Odùdúà gbéra nle ko dìde.
Ki o dìde owo.
Ki o tún dìde olà fún mi o o.
O Odùdúà, saudações!
Meu pai, que cria o comportamento.
Odua, que faz as pessoas terem boa conduta.
O harmonizador da cidade de Ifé.
O querreiro que, ao acordar, volta os olhos aos
céus.
Meu pai, que ao acordar pela manhã, anda
ativamente por toda a cidade de Ife.
O benfeitor, que não deixa as pessoas passarem
fome.
O próspero, que semeia a prosperidade na vida
dos
seres.
O bom juiz, que julga a favor ou contra.
O senhor do axé na cidade de Ife.
Odua, o vitorioso que guerreia e vence.
Ele ouviu o som da espingarda na guerra e não
fugiu.
Odudua, que aparece no ar como uma nuvem.
Ele guerreou e trouxe muitas pessoas como
escravas.
Orixá daqueles que procuram a sorte.
Tudo o que ele fala, acontece, o senhor do axé.
Tudo o que ele pensa, acontece.
Awa dé,
Awa dé o o.
O sére imale.
Awa ma dé,
Omo odúà
Awa dé o o, e e.
Nós chegamos.
Ó! Nós chegamos.
Os seguidores do òrìsà.
Nós chegamos,
Nós, filhos de Odùdúà,
Nós chegamos.
Odùdúà,
Dê-nos sorte a tempo.
Dê-nos sorte.
Divindade,
Dê-nos feliciadade a tempo.
Dê-nos felicidade.
Orin de Odùdúà (3)
Oríkì Òsányìn
Agbénígi, òròmú adie abìdí sonso.
Esinsin abèdò kíníkíní.
Òsányìn a rí ibí rí òhún.
Bí Elédùnmarè.
Aláse Ewé.
Òsányìn!
Níbo ni Òrúnmìlà nlo tí ko mú Èsù dání.
Níbo ni Òrúnmìlà nlo ti ko mú Òsányìn dání.
Aronì elésè kan soso.
Bàbá ni aláse ewé fún Òrúnmìlà àti gbogbo àwon
òkànlénígba imalè.
Aképè nígbà òrò kò sunwon.
Elésè kan ju elésè méjì lo.
A níyï káyé bí Elédùnmarè.
O gba àse ogun ta gíe-gíe.
Aronì elésè kan tí o gba olókùnrùn kalè,
Bí ení gbe omodé.
Aro abi-okó líelíe.
Ewé gbogbo kìkì òògún.
Ewé ò, Ewé ò, Ewé ò!
A pè è ni gùsú,
O Io jé ní àríwá.
Á niyi kari aye.
À npè o, wá jé wa ooo.
Omo awo ní nse òògùn.
Òsányìn wá jé wa.
O chamamos no sul,
ele responde ao norte.
Ele, que é louvado e respeitado por toda parte.
Estamos chamando por você. Venha nos atender.
É o filho do awo, que pratica medicina e magia.
Òsányìn, venha nos ouvir!
Fiwájú je.
Kotún fi èyìn je.
Omo awo ni nse òògún.
Fi òtún e gún,
Kí o tún f i òsìn e gún.
Omo awo ni nse òògun.
Kí o gún sílé o,
Kí o gún s'ode,
Omo awo ni nse òògún.
Kí ewé ójé o,
Kí òògún ó jé o.
Omo awo ni nse òògún.
Òsányìn o!
Jé ewé ó jé o.
Òsányìn o!
Jé ewé ó jé o.
Òsányìn!
Nkò da se,
Eléwé mé dà se,
Baba aròni mé dà se,
Wá fún mi.
Eléwé wá fún mi, l'àse o.
Òsányìn wá fún mi, l'àse o.
Mé dà se.
Òsányìn mé dàse o.
Òsányìn,
não faço nada sozinho.
Ó senhor das folhas,
Ó Pai Aroni , não faço nada sozinho.
Venha me dar,
ó senhor das folhas, venha me dar axé.
Òsányìn, venha me dar axé.
Não faço nada sozinho.
Òsányìn, não faço nada sozinho.
Àdúrà Sàngó
Mogbà: Ki á mà kú,
Kí á má rùn,
Kí á tún se àmódún,
Tomotomo bi àkàrà.
Adósù: Àse.
Reza de Sàngó
Oríkì Sàngó
Orin Sàngó
Mogbà: Sàngó ré ó!
Lákíyodé ó!
Sàngó rè ó!
Òrìsà ré ó.
Égbè: Sàngó dé o
Lákíyodé dé o
Sàngó dé o
Oòòsà dé o.
Mogbà: A mò pé
Odún, yabo o, e e e!
A mò pé
Odún, Yabo o, a a a,
Mogbà: Atóbájayé
Aládò nkó?
Adósù: Ó wà nlé, òòsà!
Mogbà: Odún wá dé o,
Enyìn omo Irúnmalè,
E ó se.
Tàbí, e ò ní se.
Enyìn omo Irúnmalè o.
Adósù: A ó se
Awa omo Irúnmalè o.
Eeepa Oya o!
Ma dagi ofo sile wa o
Aféjé ejó, kó ma fe lu wà ó
Séwa l'óge o
Orí mi, bá mi sé o
Orí mi, bá mi sé é é
Òrìsà Oya, bá n se tèmi
Bérin bá fan ní gbó, jìnìjìnnì, a móde e e
Oya má je ki jìnìjìnnì ó mu wáà
Oya má jé à mósì
Oya lola, j'òwó ma jósí ó kàn wá
Oya òrírì
Má jè á ríkú èwe o
Onà kó ma dí mo wà ó
Oya á j í loda
Ma f ‘idà ré bá wa wí
Oya a r'iná bom bi aso
Ma f’iná re jó wa
Efúfu lèlè ti n dági lókèlókè
Má dági léyìn kùlé wa o
Gbeijà wá jà o
Asán, òfo, kó má je tiwa o.
Eeepa Oya!
Não derrube em minha casa as árvores que
atrasam
a vida.
Oh vendaval dos problemas de justiça, não sopre
para
dentro de minha casa.
Faça-nos belos.
Meu ori, me ajude!
Meu orí, me ajude!
Oya, ajuda-me a resolver os meus problemas.
Quando o elefante barre com sua tromba na
floresta,
a alma do caçador gela.
Oya, não nos deixe com a alma gelada!
Não nos deixe conhecer a pobreza!
Oya, que possui prosperidade, faça com que a
miséria
não nos atinja.
Oya, a charmosa, a elegante,
proteja as crianças da morte.
Que o caminho não se feche para nós.
Oya, que ao acordar usa a espada,
Oríkì Oya
O tún runrun o!
O tun rénrèn.
O tún runrun o
O tún rénrèn,
I ná kó mà jó ní ipa odò.
Omo kó ma kú ó, nílé àse wàá.
O tun runrun o!
O tun rénrèn.
O tún runrun o,
O tún rénrèn.
Iná kó màjo ní ipa odò.
Omo kó ma kú ó, nílé àse wàá.
O tún runrun o!
O tún rénrèn.
Owó kò ní wón nílé àse wàá.
Aláfíà kó mà wón nílé àse wàá.
lyì kó mà wón nílé àse wàá.
O tún rúnrún o!
O tún rénrèn.
Iná kó mà jó ní ipa odò.
Cantiga de Oya (lansã) (2)
(para ser cantada após a aceitação da oferenda
feita a Oya)
O axé se espalhou!
Oh, o axé se espalhou bem!
O axé se espalhou!
Oh, o axé se espalhou bem!
Jamais haverá chamas no fundo do rio.
Ninguém que faz parte da casa do nosso axé
morrerá!
O axé se espalhou!
Oh, o axé se espalhou bem!
O axé se espalhou!
Oh, o axé se espalhou bem!
Jamais haverá chamas no fundo do rio.
Ninguém que faz parte da casa do nosso axé
morrerá!
O axé se espalhou!
Oh, o axé se espalhou!
Jamais faltará dinheiro na casa do nosso axé!
Jamais faltará àláfíà na casa do nosso axé!
Jamais faltará respeito na casa de nosso axé!
O axé se espalhou!
Oh, o axé se espalhou bem!
Jamais haverá chamas no fundo do rio.
Àdúrà Òsun
Òsun mo pè ó o !
N ò pé o s'íkú enì kankan,
béni n ó pè ó s'árun enì kankan,
mo pè ó sí níní omo.
Mo pé ó sí níní omo.
Mo pé ó si níní àláf ia.
Mopè ó sí òrò.
Kí àwa má ríjà omi o,
odoodún ní a nri orógbó.
Odoodún ní a nrí omo obi lórí àte o.
Odoodún ní kí wón má rí wá o!
Bí a se, sodún ré yií
kíá tún sé, èyí tó jù báyi lo, ní àmòdún.
Òsun sówá, kí ó máà sí wàhálà lárín àwa omo re.
Kí ilé má jòwá.
Kí ònà má nà wá o.
Pèsè àse f ún wá o.
Enì nse àmódi ara,
Fún ní àláfíà o.
Okó oba, àdá oba, kí ó ma sá wa lésè o.
Kí àwa má ri Ogun idílé.
Reza de Oxum
Oxum eu te chamo!
Não te chamo por causa da morte.
Não te chamo por causa da doença de alguém.
Eu te chamo para que tenhamos dinheiro.
Té chamo para que tenhamos filhos.
Te chamo para que tenhamos saúde.
Para que tenhamos uma vida serena.
Para que não sejamos vitimados pela ira das
águas.
Dizem que anualmente há orogbo novos na feira,
dizem que anualmente há obis novos na feira,
Que as pessoas nos vejam todo ano.
Do mesmo modo que fizemos tua festa,
façamos outra, ainda maior, no próximo ano.
Oxum, nos proteja para que não haja problemas
entre nós, teus filhos.
Para que sempre haja paz em nosso lar.
Que nossos objetivos não se voltem contra nós.
Dá-nos axé!
A quem estiver doente,
dá saúde!
Que as leis do homem não sejam infringidas
por nós.
Que não haja problemas em nossa família.
Yèyé adé-oko!
Ojó gèdè wo ojà,
Yèyé adé-oko ó se èwà lololubi,
Yèyé mi o sé èji òkè sérúsérú bí iyé ogomugomu,
Iyá mí wà lókùnkùn,
Eyín enu re ò dé búji.
Eléyín dògádògá bí enì do gaga osù.
Segede òwú.
Yèyé olómo.
Aríde g'osun.
Yèyé adé oko.
Ó dé gèdè wojà.
Ó sé ewà lólólubi.
Yèyé òpàrà!
Obìnrin bí okùnrin ní Òsun
A jí sèrí bí ègà.
Yèyé olomi tútú.
Opàrà òjò bíri kalee,
Agbà obìnrin tí gbogbo ayé n 'pé sìn.
Ó bá Sònpònná jé pétékí.
O bá alágbára ranyanga dìde.
Yèyé Opàrà!
Oxum é uma mulher com força masculina.
Sua voz é afinada como o canto do ega.
Graciosa mãe, senhora das águas frescas.
Opàrà, que ao dançar rodopia como o vento, sem
que possamos vê-la.
Senhora plena de sabedoria, que todos veneramos
juntos.
Que come peteki com Xapanã.
Que enfrenta pessoas poderosas e com sabedoria
as acalma.
Iloro re o!
Iloro kilolo
Yèyé ede o gun leti omi.
E gbó, ohun a wí.
Léyìn òrisà ní à bè.
Enì má mu derere.
Iyén a sanwó igórun-abe.
Orísà ní a bè
Enì má mú derere.
Iyén a sanwó igorun-àbè.
Orin Òsun
Òbà mo pé o o.
Sare wa je mi o,
Nitori eré gege ni t 'eku,
Akòsin kìí gbékún omo re kó dúró,
Abiyamo kìígbo-ékún omo rè kó má dide,
Òbà ojowu aya Sàngó sáre,
Wa gbo àdúrà wa o.
Bibo ti a wa bo e yi.
Ki a ma f i eleyi se a se mo o.
Bi o ba di amodun.
Ki a pò jù báyi lo o,
owó omo iyì ati àláfíà,
ki o kunle awon omo òòsa o.
Ki a má riku èwe o.
Enì n wa owó, ki o fún ni owó.
Enì n wa omo, ki o fún ni omo.
Enì n wa àláfíà, ki o fún ni àláfíà.
Só wa di amódun,
ki a tún péjo bayi,
pelu ìdùnnú se odún ré bayi o.
Reza de Òbà
Òbà, eu te chamo!
Vem logo me atender!
Porque o rato corre velozmente.
Quando Akòsin ouve o choro do filho, não fica
parado.
Quando Abiyanio ouve o choro do filho, não fica
sentado.
O cão preocupou-se,
tomaram o marido de Obá.
Obú entristeceu.
Para um caso que não se sabe como resolver,
chame a mulher de Xangô.
Para um caso que não se sabe como resolver,
chamem Obá..
Obá foi rapidamente,
Obá retornou rapidamente.
Jogún-osó,
lyemoja lòkun.
Iyá mi ni nje eran etú.
Iyá mi na ni nje eran pépéye.
Jogún-osó Iyemoja lòkun.
Olómú agu-isi.
Solá-gbadé ìyá mi a fi omo,
Téré lójú omi.
Iyá mi losun,
Iyá mi la kèsán,
Omo olókò nílé ìseri.
Iwájú olókò a ma sowó,
Eyìnkúlé olókò a ma só jìngbà ìlèkè.
Omo alagbo dudu gbolojo wo inu odo.
O de di funfun.
A lómo lésè odò.
Omo ayítu omi.
Iyá mi nse owó léjéléjé nínú omi.
Jogún-Osó.
Iemanjá, senhora no mar.
É minha mãe, que se alimenta de etù.
É minha mãe, que se alimenta de pato.
Jogún-Osó, Iemanjá no mar.
A que possui seios fartos.
Solá-gbadé, minha mãe que tem filhos
na superfície das águas.
Minha mãe, que se enfeita com osùn.
Minha mãe, mãe elegante,
que possui um barco em Iseri.
Diante da casa da senhora dos barcos brota a
prosperidade.
No quintal da senhora dos barcos brotam pérolas.
Dona do carneiro preto que, oferecido no meio
das águas, lá chegando, sob sua força tornou-se
branco.
A que tem filhos à beira do rio.
A que faz as águas se misturarem.
Minha mãe está erguendo as mãos, suavemente,
dentro das águas.
Báálé
Iyemoja àgbódò dáhùn ire
Iyá mi
Aseperiola.
Abèrìn èye lénu.
Iwo l’oko mi.
Abìrìn iyì lésè méjèjì.
Olówó orí mi.
Omi owó kò wón nílé wa,
Omi là bureke.
Iemoja a tó f’ará tì bí òkè.
O l'ómi nílé bí egbele.
Òrìsà tínfi omi tútù wo àrùn.
A wo àrùn fún olótmo má gba èjé.
Iyemoja a tún orí eni tí kò sunwòn se.
Túbò tún orí mi se kalé o.
Báálé!
Iemanjá, de dentro das águas, responde com o
bem.
Minha mãe, que pode ser chamada para trazer
prosperidade.
A que sorri elegantemente.
Você é minha senhora.
Louváveis são os passos de seus pés.
Dona do meu orí.
A água que traz prosperidade não falta em nossa
casa.
Água em abundância.
Iemanjá, firme como a montanha, nela podemos
nos apoiar.
Possui casa formada por muitas águas.
Orixá que cura doenças com água fria.
Que cura as doenças sem pedir sangue aos
familiares do doente.
Iemanjá, que melhora o mau orí, melhore mais e
mais o meu orí, até o fim da minha vida.
Òsóòsì
Awo òde ìjà pìtìpà.
Omo ìyá ògún oníré.
Òsóòsì gbà mí o.
Òrìsà a dínà má yà.
Ode tí nje orí eran.
Eléwà òsòòsò.
Òrìsà tí ngbélé imò,
gbé ilé ewé.
A bi àwò lóló.
Òsóòsi kì nwo igbó,
Kí igbo má mì tìtì.
Ofà ni mógàfí ìbon.
O ta ofà sí iná,
Iná kú pirá.
O tá ofà sí Oòrùn,
Oòrùn rè wèsè.
Ogbàgbà tí ngba omo rè.
Oní màrìwò pákó.
Ode bàbá ò.
O dé ojú ogun,
O fi ofà kan soso pa igba ènìyàn.
O dé nu igbó,
O fi ofà kan soso pa igba eranko.
A wo eran pa sí ojúbo ògún lákayé,
Má wo mí pá o.
Má sì fi ofà owo re dá mi lóró.
Ode ò, Ode ò, Ode ò,
Òsóòsì ni nbá ode inú igbo jà,
Wípé kí ó de igbó ré.
Òsóòsi oloró tí nbá oba ségun,
O bá Ajé jà,
O ségun.
Òsóòsi o!
Má bà mi jà o.
Ogùn ni o bá mi se o.
Bí o bá nbò láti oko.
Kí o ká ilá fún mi wá.
Kí o re ìréré ìdí rè.
Má gbàgbé mi o,
Ode ò, bàbá omo kí ngbàgbé omo.
Oxosse!
Ó orixá da luta,
irmão de Ògún Onírè.
Oxosse, me proteja!
Orixá que tendo bloqueado o caminho, não o
desim pede.
Caçador que come a cabeça dos animais.
Orixá que come ewa osooso.
Orixá que vive tanto em casa de barro como em
casa de folhas.
Que possui a pele fresca.
Oxosse não entra na mata sem que ela se agite.
Ofà é a arma poderosa que o pai usa em lugar de
espingarda.
Ele atirou sua flecha contra o fogo, o fogo se
apagou de imediato.
Atirou sua flecha contra o sol,
O sol se pôs.
Ó salvador, que salva seus filhos!
Ó senhor do màriwò pákó!
Meu pai caçador chegou na guerra,
matou duzentas pessoas com uma única flecha.
Chegou dentro da mata, usou uma única flecha
para matar duzentos animais selvagens.
Arrasta um animal vivo até que ele morra e o
entrega no ojubo de Ògún.
Não me arraste até a morte.
Não atire sofrimentos em minha vida, com seu
ofá.
Ó Ode! Ó Ode! Ó Ode!
Dentro da mata, é Oxosse que luta ao lado do
caçador para que ele possa caçar direito.
Oxosse, o poderoso, que vence a guerra para o rei.
Lutou com a feiticeira e venceu.
Ó Oxosse,
não brigue comigo.
Vence as guerras para mim.
Quando voltar da mata,
Colhe quiabos para mim
e, ao colhê-los, tire seus talos.
Não se esqueça de mim.
Ó Qde, um pai não se esquece do filho.
Orín Òsóòsì
Ojú oro.
Ní nwolé de omi o.
osípàtà ni nwolé de odò.
Omo-Ode má nsawo lo.
Ng o padà wá sílé o.
Òsóòsì wolé dè mí o.
Emí mà nsawo lo.
Ng o padà wá sílé.
É ojú orú
que toma conta das águas.
É osípàtà que toma conta do rio.
Omo ode está saindo para fazer awo.
Assim como saio, voltarei prá casa.
Oxosse, tome conta da minha casa.
Estou indo fazer awo.
Assim como saio, voltarei prá casa.
Òsóòsì!
Ode dà.
Ode rè.
Olú igbó dà.
Olú Igbó rè o,
Ode dà.
Ode rè o,
Omo ìyá ògún dà,
Omo ìyá ògún re.
Cantiga de Oxosse (2)
Oxosse,
Onde estará odè?
Aqui está odè,
Onde estará o senhor da mata?
Aqui está o senhor da mata.
Onde estará odè?
Aqui está odè.
Onde estará o irmão de Ògún?
Aqui está o irmão de Ògún.
Ológún-ede!
Jagunjagun nínú òrìsà.
A síwájú ogun nínú òrìsà.
Ológún-ede oporolika.
Ológún gbà mí o.
Ológún ayan fírán bí ekùn.
Lógun gbà mí o.
Ogbàgbà, tí ngba ni lójó tó burú.
Baba gbà mí, ayanfírán bí ekùn.
Baba gbà ní t’ójó tó burú.
Opopo lepon.
O mi rinrin wojo.
A gbà ni, ní ojó tó burú.
Korokoró wo o.
Elérò-odò oko.
Afenu agada jowere papa.
O fenu agada re jowere papa.
Babá mi ni a f i ara jòlò, bí igi pákó,
Eyí báwun ló nyí.
Bí ó bá yí funfun lónì,
A yí dúdú lóla,
Ológún gbà mí o.
Ó Logunedé!
Guerreiro entre os orixás.
Lidera quando os orixás guerreiam.
Ologun-pde oporolika.
Oh, Logun. salva-me!
Logun, que passa desapercebido como um
leopardo.
Oh, Logun, salva-me!
O salvador que em maus dias nos protege.
Pai, você que surge como um leopardo, salva-me!
Pai, que em maus dias nos salva.
Nas batalhas sangrentas
ele andou vigorosamente para dentro da feira.
Que em maus dias nos salve!
Que nos olhe cara-a-cara!
Dirige-se ao rio que cruza a horta.
Aquele que usa sua adaga para queimar a mata,
usou sua adaga para queimar a mata.
Meu pai, de corpo liso como o bambu,
mostra a pele que desejar.
Se mostrar pele clara hoje,
amanhã mostrará pele escura.
Oh, Logun, salva-me!
Orin Ológún-ede (1)
Baba mi.
Ológún ni asíwájú ogun.
A gbèyìn ogun.
Baba mi gbà mí.
Ológún ayan fírán.
O da oun tí o wun.
Baba di òrìsà.
Ológún di òsúpá.
Da oun tí o maa dà kín rí o,
Ológún di òsù pá.
O di asíwájú òrìsà.
Da oun tí o maa dà.
Ológún-kin.
Meu pai!
Ológún é líder na vanguarda.
Ológún é líder na retaguarda.
Meu pai, me proteja!
Ológún, que surge rápido como o vento,
transforma-se no que quiser.
Meu pai transformou-se em orixá.
Ológún transformou-se em lua.
Transforme-se no que desejar para que eu possa
vê-lo!
Ológún transformou-se em lua.
Transformou-se no líder dos orixás.
Transforme-se no que quiser,
Ológún-kin.
Onijawe mi Esùmàrè.
Mo sé òrìsà tán,
Mo yò ò, fún ara mi o.
Eyò mi, èyò.
Eni òrìsà bí ní aó yòò fún o.
Yòò, yòò fun o.
Onijawe mi fèrèjì,
Eni òrìsà bí ni ao yòò fún o.
Yòò, yòò fún o.
Oríkì Ìbejì
Mbá b í Ejìré,
Mbá jó.
Mbá bí Ejìré
Mbá yò.
Omo méjì ni Ejìré.
Tó sò ilé alákisà di aláso,
Ejìré wùn mí l'ómo o.
Edún-jobí,
Ejìré ara isokùn.
Se possuir Ejìré,
dançarei.
Se possuir Ejìré,
ficarei alegre.
Ejìré são duas crianças
que fazem o lar do malsucedido prosperar.
A ideia de possuir Ejìré é algo que me agrada.
Edúnjobí.
Ejìré vindo de Isokun.
Àdúrà Ìbejì
Reza de Ibeji
Oríkì Obalúwayé
Òrìsà jìngbìnì.
Abàtà, arú bí ewé ajó.
Òrìsà tí nmú omo mú ìyá,
Bí Obalúwayé bá mú won tán,
O Tún lè sáré lo mú bàbá,
Òrìsà bí àjé
Obalúwayé mo ilé osó, ó mo ilé àjé.
O gbá osó l'ójú,
Osó kún fínrínjínrín.
O pa àjé ku ìkan soso.
Òrìsà jìngbìnì.
Obalúwayé a mú ni toùn toùn.
Obalúwayé sí odù re hàn mí.
Kí ndi olówó.
Kí ndi olomo.
Eléní à te ká.
O rí ajé, O pá ni l pá ika.
Òrìsà Oko, a tó gbangba sùn nínú oyé.
A rí owó èyó se èsó.
Orí ògún èyó sensen.
O rí ìbon gbé re ojú ogun.
Òrìsà ti ó torí.
Akàsù iyán,
O fun won ní ogún omo.
O torí àgbébò adie,
O fún ení nwá aya,
Ní ogórun aya.
O tú fún en i nwá oko,
Ní ogórun oko.
Òrìsà oko ò ò ò
Baba o, Baba o.
Ení kúrú,
O ntiro.
Ení gùn,
O nbèrè.
Bèrè owó,
Bèrè olá ní òdò mi o,
Iwo lorí iyán.
Ti o njó bèmbé,
Iwo lo tún rí iyán,
Ti o nkan sáárá.
Òrìsà oko gulutu nlé.
Igbá funfun báláuuú.
Alágbára tí nlo fòse.
Òrìsà Oko gbè mi o,
Òrìsà oko tu mi o,
Jé ng ní nínú àse re o.
Òrìsà Oko
o loyin.
O loro.
Erin ni o rin ko mi.
O loyin.
O loro.
Orixá Oko
você possui o doce da vida,
você possui o amargo da vida.
Ao encontrar-se comigo, abra seu sorriso prá
mim.
Você possui o doce da vida,
você possui o amargo da vida.
Ó Òrìsà Oko
a grande estrela!
Orixá que é levado para a guerra,
apoie-me!
Ajude-me a ter dinheiro.
Ajude-me a ter filhos.
Ajude-me a prosperar, conduza-me nessa direção.
Òrìsà Oko
Oní lojo ìjesu.
Wá je.
Oní lòjó ijiyán.
Wá j e.
Oní lojo ìje ìká eja
Wá je
Oní lojo ìjiyán.
Wá je.
Cantiga de Egúngún
O filho tomará conta da casa durante nossa
ausência da mesma forma que a estrela toma
conta da abóboda
celeste na ausência da lua.
O filho tomará conta de casa durante nossa
ausência. Protege nossa casa como a estrela
protege a abóboda celeste na ausência
da lua. O filho tomará conta de casa durante nossa
ausência.
Bàbá ímàlè
Mo le o,
Bàbá ímàlè.
Ogberi to l'oun fé seré awo.
Bàbá ímàlé,
Mo le o,
Bàbá ímàlé.
Ogberi to l'oun fé seré awo.
Babá ímàlé, le o.
Igi ìgbàlè lê ri o,
Igi ìgbàlè.
Ogberi ki ragan wére o,
Igi ìgbàlè le rí o.
Àdúrà Egúngún
Ilè mo pè o.
Agó kìì ngbó ekún omo rè,
Kí o ma ta etí wéré,
Baba awa omo re ni a npè o.
Kí o sáré wá jé wa o,
Kí o gbó ìwùre wá,
Má jè a ríkú èwe,
Má jè a ríjà Èsù,
Má jè a ríjà Ògún,
Má jè a ríjà omi,
Má jè a ríjà Sòpònná,
Bi o bá tún di àmòdún,
Kí a tún pé jo, pèlú àlàfíà àti ayò.
Reza de Egúngún
Idowu ògbo.
Idowu aya ‘ba.
O-gún ‘yan o je,
Ídówù aya ‘ba.
Ídówù ogbo o.
Ídówù aya ‘ba.
Idowu ogbo.
Idowu, a rainha.
Ela preparou o iyan e se alimentou com ele.
Idowu, a rainha.
Ela preparou oka e se alimentou com satisfação.
Idowu, a rainha.
Idowu ogbo.
Idowu, a rainha.
Orin Gèlèdé (3)
Àgbaàgbá.
Àgbaàgbá e k’èsù odara.
Rere ng t’èsù odara rere ntèsù.
Àgba o kú o,
Omode o kú o,
Àgbaàgbá, e k’èsù odara.
Omode o kú o.
Àgba o kú o.
Àgbaàgbá e k’èsù odara.
Os sábios.
Os sábios louvam a Exu Odara
Tudo que vem de Exu Odara é bom.
Os anciãos não morrem.
Os anciãos louvam a Exu Odara.
As crianças não morrem.
Os anciãos também não morrem.
Os anciãos louvam a Exu Odara.
Orin Ìrókò (1)
A tù e lara o.
A tù e lara o.
Ero Ìrókò, a tù e lara o.
Òrìsà yí o,
A tù e lara o.
A
Abala - forma de exaltar a força e o poder de
Obaluaê.
Ara - raio.
Àrïrà - Epíteto de Xangô.
Aro - cidade da Nigéria.
B
Báálé - saudação a Iemanjá.
E
Eeepa Heyi! - saudação a Oya (lansã).
Égbè - coro.
Eku - camundongo.
Ewé - folha.
E
Ebita Okunrin - homem poderoso. Modo de referir-
se a Exu.
Etù-galinha d'Angola.
Ewà - feijão.
G
Gbègiri - sopa de feijão descascado temperada com
azeite de dendê e pimenta. Uma das comidas
prediletas de Xangô.
I
Ibà -saudação.
lyè - tempero.
J
Jogún Osó - forma de louvar lemanjá.
K
Kábíyèsí - Vossa Majestade. Expressão usada para
saudar Xangô e alguns outros orixás.
Kare o - Saudação a Oxum.
Kare o yèyè - Saudação a Oxum.
L
Laàlu - literalmente, o famoso da cidade. Epíteto de
Xangô.
M
Màriwò - palmeira. Um dos símbolos de Ogum.
Segundo o mito, Ogum vestia-se com folhas
dessa palmeira. Suas folhas são usadas como
roupa e colocadas no assentamento desse
orixá.
O
Obì - pequeno fruto de uso alimentar e sagrado.
Um dos itens mais importantes do culto
aos orixás, sendo indispensável em qualquer
ritual. É usado nas oferendas e como recurso
adivinhatório. Uma das espécies de obì é o
abatá, que possui quatro gomos em média.
Detentor de axé, pode ser comido e
oferecido aos orixás. Outra espécie é o obì
gbanja, que possui apenas dois gomos e não
serve para oferendas. Em português, obì
Ogberi - não-iniciado.
Oba - rei.
Odé - caçador.
P
Pèrègún - espécie de folha usada em rituais. Serve
também para demarcar locais de culto e túmulos
sacros.
S
Sàngó - orixá dos raios e trovões. Xangô.
Sànpònná - o mesmo que Soponna.
Xapanã.
T
Taiwo - O irmão que nasce primeiro, entre os
gémeos e que é o espírito mais novo.
Literalmente, vai experimentar a vida. Vemos nos
versos que Táyé Lolú ia na frente/e Kehinde,
devagarinho, atrás./Taiwo é o irmão mais novo/e
Kehinde, o mais velho, literalmente, o último a
chegar.
(King)
EDITORA ODUDUWA