Orin Orisa3
Orin Orisa3
Orin Orisa3
Ifá:
Mo l'árá o, mo l'ọ́ba
Mo l'árá o, mo l'ọ́ba
Àyà mi balẹ̀,
Mo l'á
Esu tiene maíz
Tengo un pariente o
Tengo un pariente o]
Ọ̀sun:
Àgò l'ọ́nà o,
Àní omi ò l'ápá, omi gbégi, omi ò l'ẹ́sẹ̀ omi gbénìyàn lọ, ìforó ayé mi ni
omi í gbé lọ
Omi ò l'ápá, omi gbégi, omi ò l'ẹ́sẹ̀ omi gbénìyàn lọ, ìforó ayé mi ni omi í
gbé lọ
Ìdààmú ayé mi
Oore Yèyé o
Oore Yèyé o
Se dice que el agua no tiene brazos, el agua arrastra el árbol, el agua no tiene piernas, pero
arrastra (se ahoga) una persona, mis problemas del mundo, el agua se llevará,
El agua no tiene brazos, el agua arrastra el árbol, el agua no tiene piernas, pero arrastra (se
ahoga) una persona, mis problemas del mundo, el agua se llevará,
El agua se llevará,
Todas las muertes nacimientos todavía temprano de los niños,
El agua se llevará,
El benéfico o madre
La madre benéfica o]
Yemọja:
Yemọja yéé, Yemọja gbàà, Yemọja gbalùbọ́sà k'ó fi rọ̀fọ́, Yemọja yòò,
Yemọja yéé, Yemọja gbàà, Yemọja gbalùbọ́sà k'ó fi rọ̀fọ́, Yemọja yòò
[Yemọja yéé, Yemọja gbàà, Yemọja gets the onion to use in preparing
the ẹ̀fọ́ greens, Yemọja yòò, yòò, yòò
Yemọja yéé, Yemọja gbàà, Yemọja gets the onion to use in preparing the
ẹ̀fọ́ greens, Yemọja yòò]
[Yemojá yee, Yemojá GBAA, Yemojá pone la cebolla a utilizar en la preparación de los verdes
EFO, yoo Yemojá, yoo, yoo
Yemojá yee, Yemojá GBAA, Yemojá pone la cebolla a utilizar en la preparación de la EFO
verdes, Yemojá yoo]
Egúngún:
Ifá:
Èṣù:
Onílé Oríta
Ògún:
Ọ̀sanyìn:
Ọbàtálá:
Ọkọ mi ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o,
Olúwa mi ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o,
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o,
Ọbàtálá dìde ó jó ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o,
Ọbàlùfọ̀n ó jó ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀,
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o,
Ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o, ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀ l'ó bá jó o, olúwa mi ó jó ṣẹ̀kẹ̀rẹ̀,
Ṣẹkẹrẹ la coctelera es lo que baila con el agitador es lo que baila con, mi señor, baila al
agitador,