Ejiogbe Ofo

Descargar como docx, pdf o txt
Descargar como docx, pdf o txt
Está en la página 1de 1

EJIOGBE OFO (prosperidade )

Ejiogbe iwo ni baba Ifa


Bi eji ogbe ba de
Oba de oba de
Ni won ki eji ogbe
Iya ki ije eji ogbe loju
Igba irunmole
Ifa maje ki iya o jewa
Orunmila maje ki osi ota wa
Ifa ke wa wole olala
Ki e wo de olola ke
Ti wa
Ko ma si nkati iwo
Eji ogbe ole gbe
Eji ogbe awa ni ko gbe lati
Ori eji ogbe awa
Ni ko gbe lati eni lo
Ase ti olodunmare
Olodunmare ase

También podría gustarte