8 Ogbè
8 Ogbè
8 Ogbè
Ogbè Òyèkú.
Ogbè Ìwòrì.
Abo akó Abo akó òld púpò òlę bònyìn bònyìn Fun işóra
lọwọ arun igbona
Ogbè Òdí.
Ogbè Òdí kaka, Ogbè Òdí lele, adífáfún Èşù, nigbi òun
fara sofa lowó Òrúnmìlá, Òrişànlá, Òrişà oko ati Ògún.
Ogbè Òdí gbèmí igbó lawo gbèmí igbó, gbèmí òdàn lawo
gbèmí òdàn, gbèmí hènhèn nìí awo gbèmí hènhen, Ifá ti o
bá yò mí ní ibi tó dí gágáágá, bí mo bá dé ibi tósunwòn
má san oore è re fún o, adífáfún Òrúnmìlá Ifá ó yo omo
rè nínú irunbi.
t. Sálveme en el bosque, es el adivino de sálveme en el
bosque, sálveme en la llanura, es el adivino de sálveme en
la llanura, sálveme en todas partes, es el adivino de
sálveme en todas partes. Ifá si usted asegura mi escape en
un enredo, cuando yo alcance un lugar cómodo, yo
pagaré ciertamente su gesto bueno de atrás, lo
profetizado por Ifá para Òrúnmìlá, cuando él iba a
arrancar a su hijo del mal.
Ogbè Òbàrà.
Síntesis profética.- Habla de enfermedades tales como
alergias de temporadas. El cliente se ha abierto camino
con dificultad en el trabajo.
Ogbè Ìròsùn.
Arère tabi igi oro Arère gbàìwò igi oro lèlújù arère
gbàìwò Ti a le fi mu ole silé
arère (árbol oro) t: árbol oro en el bosque arère árbol
grande Para detener a los ladrones Ogbè ìròsùn
triplochiton sleroxylon
Ogbè Yonu.
Okuta inu omi ni obere orun, adifa fun şotó ti’nşe omo
Bibi inu gabón niregún ebó won ni oşe osi gbebo n’be
Orugbo nje ka sotito kasadodo , eyan to sotito tosodo ni
Irunmole ogbe Ebó : akuko.
Ogbè Òsá.
Ori omo sun won baba koman, adifa fun gegbeTi renu
igbe loree gele wale , ebó ni oşe osi gbegbo n’be orugbo
iro lodora iranwa,ejin owo yegbe puropuro iro lodora
iranwa ebó :aşo ara eni akuko eyele.
Ogbè Ìrètè.
Aki laya i kokoni ngbe adije mi tori, adifa fun ope eluju
Ti ofi gbogbo araşe towo towo ebo won ni oşe , osi gbebo
N’be orugbo , ero epo, ero ora, eyin omanpe towotowo
lopeese gbogbo ara ope kiki owo ni .Ebó: eyele ,agbegbo
adije.
Etí ehoro Abetí buga buga (BIS) Lati fi lé ikú sęhin Ogbè
rí kú sá (Ogbè Òsá)
Ogbè Òtúrúpòn.
Ero ilé komopet ona nbo, adífáfún Oloide nlo ngbe Ami
ni iywó. Wón ni gbogbo ayé liomaa wa pe moo nigbi ayé
ba yewon yewon.
Ogbè Òfún.