Orikí A Yemayá
Orikí A Yemayá
Orikí A Yemayá
Àgò lònà o yá le
Àgò lònà o yá le
Yá le; Yá lù’ mọ o
Yá le omi abé; Ayaba. omi o
CORO
Àgò lònà o yá le
Àgò lònà o yá le
Yá le; Yá lù’ mọ o
Yá le omi abé; Ayaba. omi o
LIDER
Àgò lònà o yá le
Àgò lònà o yá le
Yá le; Yá lù’ mọ o
Yá le omi abé; Ayaba. omi o
CORO
Àgò lònà o yá le
Àgò lònà o yá le
Yá le; Yá lù’ mọ o
Yá le omi abé; Ayaba. omi o
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
LIDER
Yẹmọja (Ìyá) lóde
CORO
Àwoyó Yẹmọja (Ìyá) lóde
Àwoyó
LIDER
Yẹmọja (Ìyá) lóde
CORO
Àwoyó Yẹmọja (Ìyá) lóde
Àwoyó
LIDER
Yẹmọja (Ìyá) lóde
CORO
Àwoyó Yẹmọja (Ìyá) lóde
Àwoyó
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
LIDER
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
Yẹmọja fún mi lòwó
CORO
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
LIDER
Yẹmọja fún mi lòwó
CORO
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
LIDER
Yẹmọja fún mi lòwó
CORO
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
LIDER
Yẹmọja Sokún. So’kún
CORO-
A wá (A)sèsun omi Yẹmọja.
Yẹmọja e Olódò, Àwoyó Yemoja
LIDER
Yẹmọja Sokún. So’kún
CORO-
A wá (A)sèsun omi Yẹmọja.
Yẹmọja e Olódò, Àwoyó Yemoja
LIDER
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
CORO-
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
LIDER
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
CORO-
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
Ibo rere? Ibo rere o?
Àgò lònà (o)mi a wa
LIDER
Èmí ọdẹ, ọmọ dẹ, ọmọ dẹ, èmí ọdẹ
CORO
Èmí ọdẹ, ọmọ dẹ, ọmọ dẹ, èmí ọdẹ
LIDER
Èmí ọdẹ, ọmọ dẹ, ọmọ dẹ, èmí ọdẹ
Ká sù mámà iyán pele yo
CORO
Èmí ọdẹ, ọmọ dẹ, ọmọ dẹ, èmí ọdẹ
LIDER
Yẹmọja nbà wa o rí
Yẹmọja la nbà wa ẹ ke
A wa ọ rí; a wa e ké
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
Yẹmọja fún mi lòwó
CORO.
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
LIDER
Yẹmọja fún mi lòwó
CORO.
Bámbí ọ dáàrà. Ọ dáàrà bámbí
LIDER
Yẹmọja fún mi lòwó
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
LIDER
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja
CORO
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Asèsun. Asèsun Yẹmọja
Yẹmọja Olódò. Olódò Yẹmọja