Àwọn Erékùṣù Kánárì
Canary Islands Islas Canarias | |||
---|---|---|---|
| |||
Location of Canary Islands | |||
Country | Spain | ||
Capital | Santa Cruz de Tenerife and Las Palmas de Gran Canaria | ||
Government | |||
• President | Paulino Rivero (CC) | ||
Area (1.5% of Spain; Ranked 13th) | |||
• Total | 7,447 km2 (2,875 sq mi) | ||
Population (2009)[3] | |||
• Total | 2,098,593 | ||
• Density | 280/km2 (730/sq mi) | ||
• Pop. rank | 8th | ||
• Ethnic groups | 85.7% Spanish, (Canarian and Peninsulares), 14.3% foreign nationals | ||
Demonym | |||
ISO 3166-2 | ES-CN | ||
Anthem | Arrorró | ||
Official languages | Spanish | ||
Statute of Autonomy | August 16, 1982 | ||
Parliament | Cortes Generales | ||
Congress seats | 15 | ||
Senate seats | 13 (11 elected, 2 appointed) | ||
Website | Gobierno de Canarias |
Awon Erekusu Kanari (pípè /kəˈneəriː ˈaɪləndz/; Spánì: [Islas Canarias] error: {{lang}}: text has italic markup (help), pronounced [ˈizlas kaˈnaɾjas]; 28°06′N 15°24′W / 28.100°N 15.400°WCoordinates: 28°06′N 15°24′W / 28.100°N 15.400°W) je awon ile okan ti orile-ede Spain ti won je okan ninu Spanish Agbajo Adaduro ti Spain ati Agbegbe Ode ninu European Union. Ile okan yi budo si eti ariwaiwoorun bebe orile Afrika, 100 km iwoorun bode to fa ija larin Morocco ati Western Sahara. Iwo okun to yapa lati ebado Kanari lo n mo gbe awon oko oju-omi lo si Amerika.[4] Awon erekusu ibe lati eyi to tobijulo si eyi kerejulo ni wonyi: Tenerife, Fuerteventura, Gran Canaria, Lanzarote, La Palma, La Gomera, El Hierro, Alegranza, La Graciosa ati Montaña Clara.
Jeografi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Jeografi adanida
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Awon erekusu ati awon oluilu won niyi:
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ El Teide (Tenerife) es el parque nacional más visitado de Canarias con 2,8 millones de visitantes en 2008
- ↑ Official Website of Tenerife Tourism Corporation
- ↑ "Official Population Figures of Spain. Population on the 1 January 2009" (PDF). Instituto Nacional de Estadística de España. Retrieved 2009-06-03.
- ↑ "ViSioN BeTa: “Cualquier cosa que flote arrojada al mar desde Canarias, llegará a América”". Matiascallone.blogspot.com. 2006-07-11. Retrieved 2010-01-21.